Video musicale

Ìmísí
Guarda il video musicale per {trackName} di {artistName}

Crediti

PERFORMING ARTISTS
Sola Allyson
Sola Allyson
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Sola Allyson
Sola Allyson
Composer
PRODUCTION & ENGINEERING
Wole Adesanya
Wole Adesanya
Producer

Testi

Imole ko tan s'okunkun Idari ko wa lona Epo ko wa l'atupa Lai ni tan Emi mimo, mo beere (Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n'irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan Imole ko tan s'okunkun (Imole ko tan roro lati agbala, imole) Idari ko wa lona (Epo ko wa), wpo ko wa l'atupa (Ti o ni tan, ti o ni tan), lai ni tan Emi mimo, mo beere (Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n'irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan Ti o ni tan, ti o ni tan Ti o ni tan, ti o ni tan Imole ko tan s'okunkun (Itansan imole to mole roro) Idari ko wa lona Epo ko wa l'atupa lai ni tan Emi mimo, mo beere (Wa gbe mi wo), wa gbe mi wo n'irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan Oba imisi, Oba imole Oba Aanu, Oba Ogo Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Lati odo re Oba imisi, Oba imole Oba Aanu, Oba Ogo (Aanu to mu mi de bi koni ju mi le) Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Ti o ni tan Ti o ni tan, ti o ni tan (koni tan lati agbala) Ti o ni tan, ti o ni tan Imole ko tan s'okunkun (Idari ko wa), odari ko wa lona Epo ko wa l'atupa (atupa imo mi o ni ku lai-lai) Lai ni tan Emi mimo, mo beere Waa—, wa gbe mi wo n'irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan Oba imisi, Oba imole Oba Aanu, Oba Ogo Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Lati odo re Oba imisi, Oba imole (imisi lati agbala imisi) Oba Aanu, Oba Ogo Orisun imisi, Isewa imole Je ki imisi ba le mi Lati odo re (Oba imisi) Oba imisi, (Oba imole)Oba imole (Itasan Imole to mole roro) Oba Aanu, Oba Ogo (aanu to mu mi debi o ni ju mi le) Orisun imisi (ibe ni mo gboju soke si), Isewa imole Je ki imisi ba le mi Ti o ni tan (Ti o ni tan)Ti o ni tan, ti o ni tan (Ko ni tan lailai, ati agbala imisi n'imisi ti n wa) Ti o ni tan, ti o ni tan Imole ko tan s'okunkun (Idari ko wa lona mi) Idari ko wa lona (Epo ko wa l'atupa o) Epo ko wa l'atupa lai ni tan Emi mimo, mo beere Waa—, wa gbe mi wo n'irinajo Imisi ko wa fun mi, ti o ni tan Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Okun o gberi, osa o gberi o, ise Baba oni imisi ni won Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Itansan imole yen ko ma tan fun mi ni irinajo mi Lati odo Oba oni imisi, lati agbala imisi Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ko wa fun mi, ta fi irisi omo Baba imole han nigbagbogbo Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ta ko mi ni isesi imole ni gbogbo irinajo mi, lona mi Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ta fi irisi omo baba oni imisi han, ko wa fun mi nigbagbogbo Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ko wa fun mi ti o ni tan Imisi ko wa fun mi ti o ni tan
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out