album cover
Mandem
4829
Afro-Beat
Mandem è stato pubblicato il 1 agosto 2025 da Scolly Entertainment come parte dell'album Mandem - Single
album cover
Data di uscita1 agosto 2025
EtichettaScolly Entertainment
Melodicità
Acousticità
Valence
Ballabilità
Energia
BPM115

Crediti

PERFORMING ARTISTS
Islambo
Islambo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Samuel Ashaye
Samuel Ashaye
Songwriter

Testi

[Verse 1]
Hold something
Bọbọ alaṣakaṣa
Aiyayayaya
Bọbọ alaṣakaṣa
O sọnu lapa b
O sọnu lapa c
[Verse 2]
Observation no be felony
Ma ṣogun s'ọ̀gá ẹ, fowó ẹ jẹ Indomie
N gbọ, them say street no get memory
O ga o, a fẹẹ to ten story
Everybody know it’s a vibe
Gbajúgbajà ìlú mọ-ọnka yìí
Ó ń gbé wọn lọ free ride
Ó ń sọnu this side
[Verse 3]
Bọbọ kan ń pede ọmọ mi pro
Ẹ ma wo ijo lẹsẹ negro
Tó ń gbọ vibe, kò ṣe ní jó
Ti àwọn Arabo gan-an ò ṣe kó
[Verse 4]
O ya, wọ́n ti sọ d'anthem
O wa dorin àwọn mandem
Ayé ò le, ọmọ Ọba n kí ẹ
Ìwọ ló lowo inu bank ẹ
Hold something
O sọnu lapa 'bi
[Verse 5]
Ka rí nnkan jẹ, ka rí nnkan chop
I’m displaying my own caricature
In a comical way
Ẹ jẹ kọmọ yín kawe
Mo wọ club, Italo mo gbé
Eyi ara, ara kenge
[Verse 6]
Make my body no calm
Ọmọ tún ni 'yo fam'
Ẹ ni ìgbàgbó, pọja ilẹ yii yàtọ̀
Ó kan mí n'pakọ
[Verse 7]
What you saying fam, I'm going fam
Ìgbà n bá jo, lónílù gbélù (Gbelu)
Iṣẹ ọwọ Mr. Peteru
Apa, lo n jẹ the boy is very good
Ṣa làtẹ́wọ́ bí ti Cheribum
Gbe sori lati Lungu de Oniru
Bí alfa tó mọ kewu jù
London Lagos
[Verse 8]
O ya, wọ́n ti sọ d'anthem (Anthem)
O wa dorin àwọn mandem (Mandem)
Ayé ò le, ọmọ Ọba n kí ẹ
Ìwọ lo o lowo inu bank ẹ
Hold something
O sọnu lapa 'bi
[Verse 9]
O jí, ó bẹba, àtàmàlà Peckham
Everybody know it’s a vibe
Gbajúgbajà ìlú mọ-ọnka yìí
Ó ń gbé wọn lọ free ride
Ó ń sọnu this side
[Verse 10]
Bọbọ Kan n pede ọmọ mi pro (Bọbọ alaṣaṣaka)
Ẹ ma wo ijo lẹsẹ negro (Mandem)
Tó ń gbọ vibe, kò ṣe ní jó (Haibo)
Ti awọn Arabo gan-an o ṣe ko (Aiyayaya)
Ẹ ni ìgbàgbó, pọja ilẹ yii yàtọ̀
Ó kan mí n'pakọ
[Outro]
What you saying fam, I'm going fam
Written by: Samuel Ashaye
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...