album cover
Marindoti
album cover
Marindoti è stato pubblicato il 4 aprile 2025 da Olajuwon Oluwaseun Opeyemi come parte dell'album Konsoliday EP
4 aprile 2025
BPM113
Melodicità
Acousticità
Valence
Ballabilità
Energia

Video musicale

Video musicale

Testi

[Intro]
Hold something
Shi, mad o (Pound!)
Emi ti mi ti wacko (Eh)
Yeah yeah yeah yeah
Ki lẹ wọ wa party (Islambo)
O sọnu papaa 'bi
CDQ yeah yeah
Ẹsẹ mi ni ẹ wo
[Chorus]
Mu aṣọ sara
Wọṣọ to da
Eh ma rindọti
K'ajẹpako le jọ butty (Oju mi ni ẹ wo)
Ọgba wa (O wa, wọn mọ)
Amaru wa (Eh geh geh to pọ)
Azuri wa (Wọn n pe ẹ)
Ehn we dey sell chin chin
[Chorus]
Ta ba wọle ẹ ma gbọ gbigbigbi
Monster no be ṣigidi
If I'm acting fine boy Timini (Hey ey)
Wo, e get meaning (Kuro nbẹ)
Ta ba wọle ẹ ma gbọ gbigbigbi
Monster no be ṣigidi (O ti ye ẹ)
Active fine boy Timini
Wo, ṣe you know the meaning?
[Verse 1]
Filẹ, CDQ pẹlu Islambo
Aye yii kere bi Labo
High lori fashion bi Jago
Ẹru to ju owo ẹ lọ cargo
Okay, fine girl o mọ'gbo fa
But o loun o mo'ko mu
Mo n tẹwo bi Kolu
O di ileya mami sọnu
Ọlọhun nikan lo n ṣọyan
Awọn obirnin n lo kọmu
Giran-an local lo di federal
Ẹ ma fomi ata bọju
Yọgo loju ma tẹ Gucci mọlẹ
Mami alalumọlẹ
Nile epo ṣe you no see the queue
Ṣepe si to ba kin wọ sọlẹ (Woss wo'bi, woss)
[Chorus]
Mu aṣọ sara (Mu aṣọ sara)
Wọṣọ to da (Wọṣọ to tap)
Ma rindọti
K'ajẹpako le jọ butty
Ọgba wa (O wa, wọn mọ)
Amaru wa (O wa, to pọ)
Azuri wa
Ehn we dey sell chin chin
[Chorus]
Maṣọ sara (Irinisi ni isọniloko)
Wọṣọ to da (Sorry ni isọnilọjọ)
Ehn ma rindọti
K'ajẹpako le jọ butty
Ọgba wa (ṣile kan ten kobo)
Amaru wa (Ni pọkulowo ten kobo)
Azuri wa
Ehn we dey sell chin chin
[Verse 2]
Ta ba wọle ẹ ma gbọ gbigbigbi
Monster no be ṣigidi
If I'm acting fine boy Timini
Wo, e get meaning
Ta ba wọle ẹ ma gbọ gbigbigbi
Monster no be ṣigidi
Active fine boy Timini
Wo, ṣe you know the meaning?
Written by: Olajuwon Oluwaseun Opeyemi, Sodiq Abubakar Yusuf
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...