album cover
Ewe
album cover
Ewe è stato pubblicato il 18 novembre 2020 da YBBM come parte dell'album Alagbe
AlbumAlagbe
Data di uscita18 novembre 2020
EtichettaYBBM
LinguaEnglish
BPM82
Melodicità
Acousticità
Valence
Ballabilità
Energia

Video musicale

Video musicale

Testi

Petrol hydro canabino
Ewé dùn, lebe-lebe le oh, (ewé)
Lebe-lebe-lebe-lebe oh
Ewé dùn (ewé oh)
Lebe-lebe le oh (ewé oh)
Tórí, tèmi bà r'ewe inú mí à dùn (ayy)
Ará mí à ya ga-ga oh (ewé dùn)
Làtete kòṣe Bàbá tí d'ewe
Ewé ọlá, ewé àlàáfíà
Ewé mà múní l'aradà
Ewé dá f'àgbàlagbà, ewé dá fún àwọn ewe
Ewé dùn bí omidùn
Ẹfọ ugwu no be kanaku
Ó yatọ s'ewe ewedu
O yatọ s'ewe akoko
Bàbá, ìwọ ló ń d'ewe f'awa èwe
Ó ní k'aja lóko, k'asa k'ọgbẹ́, kà we laṣọ, kà f'ina sí
Ibà f'àwọn ọmọ mí èwelé
Eléwé ń j'ewe, wọn j'ewe lọ (ewé)
Pé ìlú ódà, ìlú ódà, wọn f'ewe ṣàyé lọ (f'ewe ṣàyé lọ)
Qdot lórúkọ mí (ewé oh)
Ẹ fún mí ní ewé oh
Ewé ọla, ewé àlàáfíà
Ẹ bá mí we ewé oh
B'ina yẹn ó lekú, tí ń báti rí kanaku
Ẹ fún mí ni ewé oh
Ewé ọlá, ewé àlàáfíà
Ẹ bámí we ewé oh
B'ina yen o leku, tí ń báti rí kanaku
If the trouble turn in the ghetto if in your eye
If your brain no strong, brother, run away (away)
Kò ṣe fí s'ara kú, ma ṣ'afara we o (ewé oh)
Ọlọrun mí ga, emí náà à ga, tí ń ba tí gbé'wé lu'ra
Rọra ṣé oh, rọra ṣe
Ọmọ ẹmí, rọra ṣe
I believe I can fly (higher)
Òní cigar fọ f'onigbo
Onigbo ń fọ fún ẹlẹ'S.K oh
S.K ń fọ fún paw-paw oh
Paw-paw padà fọ fún Arizona oh
Arizona, padà fọ fún loud oh (yeah)
Pé ta'loni loud fọ fún Colorado (e yayy-yy, e yayy-yayy) (ma we)
Latete kòṣe l'ewé tí wá (mà we)
Baba ló d'ewé pẹlú egbò (mà we)
Òun t'Ọlọrun dá, dára-dára ni (mà we)
Kó lé yí wá lórí oh (mà we)
Ó ma ń wú mí lórí oh (mà we)
Erúku Elegusi tó ni iru (mà we)
Tó fi dé Ikeja lọdọ Baba Fela (mà we)
Àwọn tèmi l'Oniru oh (ma we)
Dé aládùúgbò wọnú Laketu (ma we)
Ita Aro, àyé ò pare (ma we)
Nísàlẹ̀, a mà dé down, down, down (ma we)
Lẹgbẹ church àwọn mummy mí (ma we)
K Sir Sosse no dey smoke the kpoly (ma we)
Shout out to Baddy Ooshaa (ma we)
Shout out to Lanre Typical (ma we)
Milli Hustle, ọmọ Salawe (ma we)
Xsmile, f'arabale bá ń yí (ma we)
Málọ gb'ọja wọ Dubai (ma we)
(Yeah, who's here?)
Ah, fire burn the wicked
Àwọn to ni ka ma mú igbo weekend

Loading...