Testi

Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo Oluwa Olorun Eledumare to poo ni pa ati agbara Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo Gbogbo iseda soo bee eemi na soo bee Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo Lati oogun eemi mi Mo juba re Ooba mimo Awa ma ri di Oluwa Mowo le fun Ooba toto Leyin ree ko si ooo Iwo to wa ni pekun kun imole Iwo ni ekun ola ekun oogbon ekun agbara Iwo nikan ni Ooba Mo juba re Ooba mimo Ooba to joko sori ite Ooba to wa lori obiri aye ma se Oola re loo Mowo le fun Ooba toto Leyin ree ko si ooo Aye ati Oorun nkoo ko si elomi To ye ko gba ijuba wa bi o se Iwo Iwo nikan ni Ooba Mo wa ri fun ooo Oolola Pelu iwa riri lati oogun emi mi Imole to tan sinu okunkun mi Ogo fun okoo re Leyin Oluwa Leyin ree ko si ooo Ko se lomi Iwo ni Leyin re Iwo na ni ma sola re lo Oluwa Iwo nikan ni Ooba Leyin ree ko si ooo Olugbemiro Olusainumi Olukemi Olufunmilebun Olugbemiro Iwo ni kan Olutimileyin Iwo ni Iwo nikan ni Ooba Mimo ni ooo mimo ni ooo mimo Aye ati Oorun soro ogo re afi ise Oowo re won Iwo mimo Mo da oun mi poo moo gbogbo ise re Emi e imimi ati emimi ayin ooo ni gba gbogbo Ooba to wa ni ipekun ola ipekun ogo ipekun agbara ipekun ewa Iwo nikan ni Oluwa Pepe na loda Oluwa Pepe ni ooo pepe ni ooo pepe Talo le yo koro ninu re nigba ti a ti e emo ooo Pepe ni ooo pepe ni ooo pepe Yiye ni ooo yiye ni ooo yiye Iwo na lowa fun rare Iwo ni Oluwa Yiye ni ooo yiye ni ooo yiye Odo Agutan to Jo ko sori ite oooo yiye Tito ni ooo eleda gbogbo eniyan Tito ni ooo tito ni ooo tito Olotoju gbogbo eniyan Olorun gbogbo a re Eniti to ngbo adura odore la wa Iwo ni Tito ni ooo tito ni ooo tito Gigun ni ooo gigun oooo gogun Ooba to joko so iri obi ri aye O fi aye sole sori awon isan omi aye ole ri Lailai kole ri ise re ni gigun oo gun Lai lai Mo juba re Oluwa Mo juba re oba mimo Emi mi juba re nigba gbogbo Mo wole fun ooo Baba Mo wole fun oba toto Leyin re kosi elomi Leyin re eee kosi ooo I confess kosi elomi Olorun Eledumare to poo ni pa ati agbara Iwo nio Olorun awon omo ogun Iwo nikan Iwo nikan in Ooba Mo juba re oo baba Mo juba re Ooba mimo Tani ba juba bi oo se Iwo Olori Egbegberun ogun awon angeli Iwo ni Mo wole fun Ooba toto Oludaye kosi le lomi Leyin re kosi ooo Aseda gbogbo eniyan Olorun gbogbo ede Olorun gbogbo eya Iwo Iwo nikan Iwo nikan ni Ooba Mo wari fun ooo Olola Emi mi eemi mi ati emi na Imole tio le ku lailai Imole to tan sinu okunkun mi Ogo fun oko re Lehin re (baba) kosi oooo Olugbemiro olusanumi olugbamila oluyomi ninu okunkun Iwo nikan ni Ooba Lehin re kosi oooo Tani ba sin ti o se eni tio gbamila Eni ti mio ri sugbon ti mo ri isere ninu ayee mi Iwo nikan ni Ooba Olorun gbogbo araye Iwo nikan ni Olutoju gbogbo eniyan Iwo nikan ni Mo kio kio Iwo nikan ni Ooba Ma shola re looo Ma shola re looo Ko se lo mi You are the only one You are the only one Iwo nikan Holy mimo mimo ni oo Iwo ni Ooba Iwo nikan ni Ooba
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out