歌詞

Jerryson production MashaAllah Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira K'eda sise bi erin, je ije eliri Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira K'eda sise bi erin, je ije eliri Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye Mo koseri doju ami, mosi gbominira Igba tao r'owo gba shop, oju rito o laye Anforiro t'ifarada pe toba pe o boya P'ori ton suffer apada wa d'ori olola Olohun o dojutimi, o funmi lona miran Ofise orin damilola, koma tun funmi lasan O semi ni arisami t'aye nri tonfola ke Kon to p'akoko tabikeji, won a 'oriyomi sha Kìràkìtà mi lotunlosi oba oluwa, lofi demilade Kìràkìtà mi lotunlosi, oba oluwa lofi demilde Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira K'eda sise bi erin, je ije eliri Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye Bee Loju olowo oledabi, bi pawon logbon Loju talika yio maro polowo je tete Etò l'olohun fisoro yi k'aye le segbe Gbogbo eni tonfori ro kosikosi o laye Olohun a sina yio pada da loju emi won Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira K'eda sise bi erin, je ije eliri Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye Gateman to ns'olode ati wole olowo Nigba tio i rise yen, ogbon kobosi londa Nigba tobosi opada di gateman olowo Ori b'olowo se nfayo je aye olola O wa nsadua k'olohun soun naa lolowo T'adua tonse bapada gba toba d'olola Selomi ko nio pada ma sole olowo? B'aye seri leriyen eto Olohun loje Ise tenikan sowipe ko kamo to tesiwaju Ope lomaje felomi toba rise yen gbamu Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira K'eda sise bi erin, je ije eliri Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye Aseda mafimi sile seun taye mi nfe Kinma d'iwole kinto pada gba oore timo nwa At'iwe timo tun rika, je nrola fi muwa Kinma fogbon pelu idea mi gbaye inira Oba je k'aye fise mi lomi, tola finde K'atiga layemi madeti, maje kole nira Imo atoye topeye wumi kin r'aye gbe Isoro masomi d'ode nibi tobaye fogbon Jeko dara funmi o, kinma w'aye inira K'eda sise bi erin, je ije eliri Kìràkìtà mi lotunlosi, je koja sire Oba maje r'idamu, kin mase w'aye alaye Aoni damu kato lowo lowo Ise kekere owo nla ni kabawon se Ise kekere owo nla ni kabawon se Katodeni tayenfe isenla lase Katodeni tayenfe isenla lase Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa Gbogbo wa laojo lowolowo Gbogbo wa laoma kolemole Gbogbo wa laoma ni lari Aoni damu kato lowo lowo Ise kekere owo nla ni kabawon se Ise kekere owo nla ni kabawon se Katodeni tayenfe isenla lase Katodeni tayenfe isenla lase Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa Ibi tegbe wa tin nawo kama na tiwa Agbara lola tonije maje ko dole Maje kosaini maje ko toshi Ike ti koranti bere kobanfun Ola ti koranti bere kobanfun Aponle to ntowo re làwã bangbe fun Agbara lola tonije maje ko dole Maje kosaini maje ko toshi Ike ti koranti bere kobanfun Ola ti koranti bere kobanfun Aponle to ntowo re làwã bangbe fun Hajji lateef olumegbon alakanni mi Olanrewaju amuludun accra ghana Olumegbon ntoju mi fun t'owo t'ola On gbiyanju k'aye timowa rorun Bose nfife hanmi malo nfowo momi Amuludun gbogbo accra ni ghana Ola ti koranti bere kobanfun Aponle to ntowo re lawa, bangbe fun Agbara lola tonije maje ko dole Maje kosaini maje ko toshi Ike ti koranti bere kobanfun Ola ti koranti bere kobanfun Aponle to ntowo re làwã bangbe fun Olohun tunbo ke latifu bose ngbero Koje kola e tunbo fe dori omo Toripe lojumo nimo nsadua fun At'adua topo eniyn nse fun Tiru e balo pe mefa laye mi, dangote afe bami sore ni dandan Olanrewaju akanni maje owo e lo Kawa tanje ninu e le gbadun si Ike ti koranti bere k'olohun fun Ola ti koranti bere k'olohun fun Aponle to ntowo re làwã bangbe fun Agbara lola tonije maje ko dole Maje kosaini maje ko toshi Ike ti koranti bere kobanfun Ola ti koranti bere kobanfun Aponle to ntowo re làwã bangbe fun Ha, olanrewaju da pupo Aye ngba fun e Oko mosunmola big hajjia, summaiyah Oko abebi aliyah, queen of queens Baba yetunde baba mariam Baba olansile baba kolayemi, ese gan Al'olumegbon da pupo, aye ngba fun e Mofeyale rashidi amole jeje Dandan ni kinyale rashidi amole jeje Baba onile tuntun rashidi amole jeje Ilenla to koyen o mani jona Eyi to tiko tele o mani wo lai Eyi to tunku tomako o mani nira Ha, omotosho rashidi amole jeje Meter meter lowomi oteyi mo moore Olohun ma gba alafia ara amole Olohun mafi towa lenu wo ko funwa tan Amole o seni laàbò odidi ni Jejelayegba oko basira, oko shukura Oko fatima (alase jeje haulage ebudola) Bami k'alhaji ibrahima ishola popoola Oko anifa oko maria, baba afusa baba amira Oni maf'amole towa lenu wo ko funwa tan Amole o seni laàbò odidi ni Bo l'olawale maso p'òleyan, yusufu omo olaegbe da o Atiwa atise yusufu lo sunwon Eniyan lomo olaegbe sha Gbogbo iwa e malo temilorun Baba ilyas baba zainab Baba Khalid baba oni maleek Olaegbe sore mawobe, o sore Olawale jeni togbayi, o sore Ha, toripe rere malo nf'ojo aye e se Aye nroyin e yusufu, wipe oseniyan gan ni Saraa lon fojo aye e se Aye nroyin e lawale, wipe oseniyan gan ni Eniyan toba nioma sore Ojeya tete sun kuro, fawon ton dena oore Eniyan tobani omale sore Ojeya tete sun kuro, fawon ton dena oore Yusufu o tun wani sore Kotun wa gaba lori e, konireti ope mo Olohun onije omale sore Toriyen ma lola nwo, tiofile jola o tan Ore oni gbowo e kodiiiiii bi o Ore o ni gbowo e ko dibi Tor'aniyan toma nlo, tonitoni ma lonmo Mo l'onilenla moleniyan toga Moleniyan toga Abbey de don, abbey de don, onilenla Prince abiodun nilu germany, onilelenla Alhaji alafe qomarudeen, onilenla Baba saida baba gbolahan, onilenla O loke timo gbero lati fo, ma debe Oun tobagba lama fun, ma debe Ao kan nikoja aye wani, ma debe Oloke tingbero lati fo Maa debe Moki saheed omo olayode Olatunde oko ejire amina Alase olateed olaoluwa, baba olamiposi jamal mi Baba ayomide azeezah mi Baba korede mi adigun Mentioning the names of die hard fans Fun publicity won ngbiyanju o Hajji rashidi akanmu agba Omo bakare akanmu agunwa Alase gloryland daddy mi agunwa Alhaji nurudeen rereloluwa Do good adedunmoye mi Adisa oko alhaja abiba, oko alhaja nasiro Alase ademola oba estate Ema ku itoju mi oriyomi Alhaji riliwan cooler olori Oloriodo leni timowi Oloriodo ijora kingdom Hajja rofia obadara mi Ara99 tonje arike, mama shubomi alaniade Artist manager mi oriyomi Innocent ahmed ayesoro Manager mi baba adulrahman Baba basit baba aliyah mi Moki ismaila adisa ade Ayomide emir 1 Moki owolabi mi anisere Lookman baba faoziyah Baba aliameen baba awwal Jerryson production to tatata Pelu hajji qubar engineer mi, ese O loke timo gbero lati fo, ma debe Oun tobagba lama fun, ma debe Ao kan nikoja aye wani, ma debe Oloke tingbero lati fo Maa debe
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out