album cover
Ìrìn Àyànmọ́
album cover
Ìrìn Àyànmọ́은(는) {albumName} 앨범에 수록된 곡으로 2022년 7월 7일일에 THE SOLAALLYSON LIMITED에서 발매되었습니다.Ìmísí
앨범Ìmísí
2022년 7월 7일
라벨THE SOLAALLYSON LIMITED
BPM91
멜로디에 강한 음악
어쿠스틱 악기 중심
발랑스
춤추기 좋은 음악
에너지

뮤직 비디오

뮤직 비디오

가사

Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba r'oko, ma ba o lo
Bo ba r'odo, ma ba o lo
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba r'oko, ma ba o lo
Bo ba r'odo, ma ba o lo
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
A rin ree, a rin ree
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
A rin ree, a rin ree
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Ikoro o ni wo aye wa
Amin oh
Adanu o ni wo be
Ase
Alagbeda o ni gbe wa da
Amin oh
Anu a bo ri asise
Ase
A ba ra wa rin rinajo kale
Amin oh
Ikoro o ni wo aye wa
Ase
Adanu o ni wo be
Amin oh
Alagbeda o ni gbe wa da
Ase
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba r'oko, ma ba o lo
Bo ba r'odo, ma ba o lo
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
A rin ree, a rin ree
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
A rin ree, a rin ree
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Ikoro o ni wo aye wa
Amin oh
Adanu o ni wo be
Ase
Alagbeda o ni gbe wa da
Amin oh
Anu a bori asise
Ase
Ninu gbogbo iriri, iranwo a wa
Amin oh
Anu wa lona, o fisegun kpa gaja
Ase
Anu lai nitan barawa jo
Amin oh
Imole lai niku tan lona wa
Ase
A ba ra wa rin rinajo kale
Amin oh
A o ni f'ese ko okuta lona wa
Ase
Awon angeli wa gbe wa ni owo won
Amin oh
Aromo domo ati oledole, ire
Ase
Ire ati anu yo ma tele wa nigba gbogbo
Amin oh
Iseda bi iranwo jade fun wa
Ase
Anu a bori asise
Amin oh
A ba ra wa rin rinajo kale
Ase
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba gbe igba, ma ba o gbe
Bo ba gbe agbon, ma ba o gbe
Bo ba r'oko, ma ba o lo
Bo ba r'odo, ma ba o lo
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Bo ba reperi okun, bo ba reperi osa
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
A rin ree, a rin ree
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
A rin ree, a rin ree
Ìrìn àyànmọ́ lo pawapo, a rin ree
Written by: Sola Allyson
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...