album cover
Forever
album cover
00:30
01:20
00:00
02:30
Ostatnie 7 dni
Forever był najczęściej odkrywanym utworem w czasie około 40 sekundy do w ciągu ostatniego tygodnia

Tekst Utworu

On our wedding day, a ma gbe su le na
This our love story, I'm not giving up
Would you ride with me, ahh, Olufumi
Ohh, I'm mad over you, girlie
Ama bimo meji meta
Calm down, kó dé gboríwà
Oh my baby, you go concur
I go give love pẹ̀lú jara
Ife wa dé, ma ṣàn jọ
Love you now till whenever
Ife ile-iyelé ni, bó bá ẹ lọ, mo bá ẹ lọ, ah
And if you do me jeje
I go do you tender
Kò rù, ká ti dé owó náà
And you can have all my cheddar
Mo ti jẹ dòdò, mi ò lè sọ òdòdó mọ
Ehhh yaaah
Bó dé ṣe máa jẹ́, mo fara mọ́
When you call, I concentrate
Ìwọ ló gbé mi trabà
I won know where you dey
(Where you dey)
Orí má ń fún mi when you no dey, ahh
Oh my baby, smokingta
Love wey I no fit buy
Mi ò lè rí rẹ̀ rà l'ọjà
Ama bimo meji meta
Calm down, kó dé gboríwà
Oh my baby, you go concur
I go give love pẹ̀lú jara
Ife wa dé, ma ṣàn jọ
Love you now till whenever
Ife ile-iyelé ni, bó bá ẹ lọ, mo bá ẹ lọ, ah
And if you do me jeje
I go do you tender
Kò rù, ká ti dé owó náà
And you can have all my cheddar
Mo ti jẹ dòdò, mi ò lè sọ òdòdó mọ
Ehhh yaaah
Bó dé ṣe máa jẹ́, mo fara mọ́
Written by: Giwa Quadri Ayomikun

Loading...