Lyrics

Bopolo se nyo loju elegusi ko ku le fi jeun Gboro mi ro baba Kaye mama sun mije o See everywhere I dey go people dey hail my name now No dey walk alone like my liver polo Mo ti rirapada Iyanu ti sele o Okan mi ti bale Anyone wey try choppu na now Mo ti rirapada o Iyanu ti sele o Okan mi ti bale Anyone wey try choppu na now eee Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Oluwa, Oluwa, Chineke is involved Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Is involved Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Oluwa, Oluwa, Chineke is involved Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Is involved Qdoti loruko mi Won gbohun soke so nile keu Mo seri mo da fa laafin orun Hijira le, hijira mi sauda Adaba ti ko le fo, omo araye lo sun da Awon asebi n binu wa, tori awon o biru wa Oyinkade pelu Qdoti E ole masiri wa Tori ewure ole gato malu Lasma ole momo yahoo Hijira le, hijira malaika seri bumi Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Sakaburi Sakaburi Oluwa, Oluwa, Chineke is involved Senseburi Sadaseri nabana Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Seli seli mayafuri Is involved Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Oluwa, Oluwa, Chineke is involved Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved Oluwa is involved, Chineke is involved Ole le le le Ele le le le Sele ole le le le Ele le le le Sele ole le le le o Ele le le le Mba ole le le le le le le o Ele le le le Obami atobajaye Iwo lo n gbe leke aronipin o Iwo lon fun mi loroso laarin egbe Baba Oya mo ki o pe yaba yabo sha o Baba Hey hey hey ihe hey hey yah ah
Writer(s): Oyinkanade Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out