Lyrics

Marley naira Pounds oun segbe dollar Won kin no bredi no dey dull am O wun emi na kin lo j'amala pekam Ogologo Ogo to le kongo Ogologo Ogo to le kongo Ologo rainbow Osha propro Ogologo lyrical mafia emi ogbologbo Ogologo Mo n korin mo tun mo ijo jo Ogologo Mo mowo mo tun mo oju obo Ogologo Mo mo iwe mo tun mo Igbo we Ogologo Ori olori lo nlo eran Iya oshogbo Lagbara fu ro ké lo gbé agbara le Agbo zanku la wa ké lo bo agbara le Iphone x-mas e ma lo jé oja bo le Awon Omo wase? Eleha to si sardine àwo ri àwo O fẹ wá mí wálé kò wá bà mí là gbó Je ka rí ra Later àbí ká pàdé lá gbó Àwa má rí má kò ẹyin ká rí ká sho Never broke again àwọn ìjọba ceecee Chevrolet camaro ya tó infinity Ara utility mi ò ní gungirity Má tá fele fele Come My vicinity Garri ó need ìpolówó Àti mo pé ẹni Mission Ọlopa mú ẹ ó ní kó má gbé e gba títí Ọmọ àṣẹ kò sá tí de Station Ogologo Ogo to le kongo Ogologo Ogo to le kongo Ologo rainbow Osha propro (Osha pra pra) Ogologo Lyrical mafia ẹ mi ogbologbo Ogologo Mo n korin mo tun mo ijo jo Ogologo Mo mowo mo tun mo oju obo Ogologo Mo mo we mo tun mo Igbo wé Ogologo Ori olori lo nlo eran Iya oshogbo Osha lè fo fún adìẹ Osha lè do mummy ẹ Olosho tún lè sha Daddy ẹ Bí Zlatan Sọ lè gbé body ẹ A Sha lè fò fún adìẹ Osha lè do mummy ẹ Olosho tún lè sha Daddy ẹ o Bí Zlatan sọ lè gbé body ẹ Ìtumò ìtumò yẹ ìtumò ye Abu Abel ó bá má? Alaye ṣe bí o kàwé sebi ó Mọ wé Ó tún wá rí ìṣe láyé Sọ rí pé oje lọ láyé Lọ ra lappy kò wá hacker sì Malay Arin giniginini arin gini Arin ginini wó ọjà Ilé mọ wo di ilé owó Ọna mó gbá ọ'nà mọ gbá di ọ'nà ola Àpótí mó fi joko àpótí ajé Ìyẹn di àpótí alaje Òkè àgbà ní mo gùn òkè àgbà òkè àgbà ní mó gùn Cblack Marlians (mafians) Ogologo Ogo to le kongo Ogologo Ogo to le kongo Ologo rainbow Osha prapra
Writer(s): Azeez Fashola, Fuwad Nurudeen, Qudus Olamilekan Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out