Lyrics

Petrol hydro canabino Ewé dùn, lebe-lebe le oh, (ewé) Lebe-lebe-lebe-lebe oh Ewé dùn (ewé oh) Lebe-lebe le oh (ewé oh) Tórí, tèmi bà r'ewe inú mí à dùn (ayy) Ará mí à ya ga-ga oh (ewé dùn) Làtete kòṣe Bàbá tí d'ewe Ewé ọlá, ewé àlàáfíà Ewé mà múní l'aradà Ewé dá f'àgbàlagbà, ewé dá fún àwọn ewé Ewé dùn bí omidùn Ẹ'fọ' ugwu, no be kanaku Ó yatọ s'ewe ewedu O yatọ s'ewe akoko Bàbá, ìwọ ló ń d'ewe f'awa èwe Ó ní k'aja lóko, k'asa k'ọgbẹ́, kà we laṣọ, kà f'ina sí Ibà f'àwọn ọmọ mí èwelé Eléwé ń j'ewe, wọn j'ewe lọ (ewé) Pé ìlú ódà, ìlú ódà, wọn f'ewe ṣàyé lọ (f'ewe ṣàyé lọ) Qdot lórúkọ mí (ewé oh) Ẹ fún mí ní ewé oh Ewé ọ'la, ewé àlàáfíà Ẹ bámí we ewé oh B'ina yẹn ó lekú, tí ń báti rí kanaku Ẹ fún mí ni ewé oh Ewé ọlá, ewé àlàáfíà Ẹ bámí we ewé oh B'ina yen o leku, tí ń báti rí kanaku You fit turn in the ghetto if in your eye If your brain no strong, brother, run away (away) Kòṣe fí s'ara kú, ma ṣ'afara we (ewé oh) Ọlọrun mí ga, ẹ'mí náà à ga, tí ńba tí gbé'wé lu'ra Rọra ṣé oh, rọra ṣe Ọmọ ẹ'mí, rọra ṣe I believe I can fly (higher) Òní cigar fọ f'onigbo Onigbo ń fọ fún ele 'S.K oh S.K ń fọ fún paw-paw oh Paw-paw padà fọ fún Arizona oh Arizona, padà fọ fún Loud oh Pé ta'loni Loud fọ fún Colorado (e yayy-yy, e yayy-yayy) (ma we) Lat'ete kòṣe ní ewé tí wá (mà we) Baba lódá ewé pẹ'lú egbò (mà we) Òun t'Ọlọrun dá, dára-dára ni (mà we) Kólé yí wá lórí oh (mà we) Ó ma ń wú mí lórí oh (mà we) Erúku Elegusi tóni iru (mà we) Tófi dé Ikeja lọ'dọ' Baba Fela (mà we) Àwọn tèmi l'Oniru oh (ma we) Dé aládùúgbò, wọnú Laketu (ma we) Ita Aro, àyé ò pare (ma we) Nísàlẹ̀, mà dé down, down, down (ma we) Lẹgbẹ church àwọn mummy mí (ma we) K Sir Sosse no dey smoke the kpoly (ma we) Shout out to Baddy Ooshaa (ma we) Shout out to Lanre Typical (ma we) Milli Hustle, ọmọ Salawe (ma we) Xsmile, f'arabale báń yí (ma we) Málọ gb'oja wọ Dubai (ma we) (Yeah, who's here?) Ah, fire burn the wicked Àwọn toni k'ama mú igbo weekend
Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out