Music Video

Tèmi Nì Tèmi
Watch {trackName} music video by {artistName}

Credits

PERFORMING ARTISTS
Brymo
Brymo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olawale Olofo'ro
Olawale Olofo'ro
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Mikkyme Joses
Mikkyme Joses
Producer

Lyrics

Ife mi dari jinmin Omo de nse mi Afarawe o se temi Ka da duro ni mo wari Moti so tele tele ri Igboro o ma rerin ri Ijakadi lomu nise Ka ro'nri o b'opo sise Bi nba fa a, won l'ole Bi nba tule, won lo ro Bi nduro won ma mu'ere Bi nba sa won ni mo kere Aba lo aba bo Bo wunwon kan'para won Owun ani lan nani Temi ni temi Awelewa f'ori jinmin Mo lokaaka kin to debi Riro mede o se temi Nibi lile lan b'okunrin Ife re sa loduro timi Odudu ofunfun o pupa Ife re sa lon'munu tumi Ninu eerun at'ojo at'ailera Bi nba fa a, won l'ole Bi nba tule, won lo ro Bi nduro won ma mu'ere Bi nba sa won ni mo kere Aba lo aba bo Bo wunwon kan'para won Owun ani lan nani Temi ni temi Aba lo aba bo Temi lo je la'le oni o Gbogbo igba ti o oba lo Mo mo o pada wa
Writer(s): Olawale Olofo'ro Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out