Music Video

Ọlánrewájú
Watch {trackName} music video by {artistName}

Credits

PERFORMING ARTISTS
Brymo
Brymo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olawale Olofo'ro
Olawale Olofo'ro
Songwriter

Lyrics

Igba o lọ bi orere Bo ba koro, oṣi maa dun ah Eni to ni suuru, kii ṣeyan kekere Bo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah Boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e (ẹh a ẹh) Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ (ẹh a ẹh) Ọlanrewaju ọmọ ọba E ma suure da gba, won ni ko o ṣe were, roora ṣe E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo Olanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba oo Igba o lọ bi orere Bọmọde oku oo, oṣi maa da gba Ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ Oun tio to o, oṣi maa pọ da nu Gbogbo eni abi lo ma ku, eh Eh a ẹh Iwa ta a wu lo ma ku (ẹh a ẹh) Ọlanrewaju ọmọ oba, e ma suure da gba o Won ni ko ṣe were, roora ṣe E ma suure da gba oo Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo Ọlanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba o Olooto ko ni ku sipo ika oo Olooto ko ni ku sibi ote oo Ọlanrewaju ọmọ ọba, ee ma suure dagba oo Ọlanrewaju ọmọ mi, ee ma suure da gba oo
Writer(s): Olawale Olofo'ro Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out