album cover
Tikuku
album cover
00:00
00:20
00:30
00:40
00:50
00:55
01:05
01:20
01:40
01:45
02:10
02:20
02:25
02:40
00:00
02:55
Past 7 Days
Tikuku was discovered most frequently at around 20 seconds into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Intro]
(Yo)
(Chocolate)
Ladies Dragon
(Yo Rexxie pon this one)
Mafe, wo
[Verse 1]
Who dey give una liver?
I go chop una dinner
We dem boys, awa leeyan Khalifa
Help me talk to my dealer
Make he bring my -, wa oh
Ọmọ, me, I wan biza oh
[Verse 2]
Sọ fun wọn k'ọn ṣe jejẹ
K'ọn ma lo f'ori bẹ
Person wey get 2,500 no fit do dorime
Sọ fun wọn k'ọn ṣe jejẹ
K'ọn ma lo f'ori bẹ
Person wey get 2,500 no fit do dorime
[Verse 3]
Hope say you go dey tomorrow and every day?
Ọmọ, baby, mi o le ṣalaye (Ọmọ, baby, mi o le ṣalaye)
Molly ti mo gbe ati jombo ti mo gbe
Hennessy ti gbe mi trabaye (Hennessy ti gbe mi trabaye)
[Chorus]
Ẹ fẹ la (Ẹ fẹ la)
Ẹ fẹ jo (Ẹ fẹ jo)
Ẹ fẹ tikuku (Ẹ fẹ tikuku)
Ẹ ma jo se (Ẹ ma jo sẹ)
Wọn ma la (Wọn ma la)
Wọn ma gbẹsẹ (Wọn ma gbẹsẹ)
Wọn ma tikuku bi ti Poco
Ẹ fẹ la
Ẹ fẹ jo
Ẹ fẹ tikuku
Ẹ ma jo sẹ
[Verse 4]
Sọ fun wọn k'ọn ṣe jejẹ
K'ọn ma lo f'ori bẹ
Person wey get 2,500 no fit do dorime
Sọ fun wọn k'ọn ṣe jejẹ
K'ọn ma lo f'ori bẹ
Person wey get 2,500 no fit do dorime
[Chorus]
Ẹ fẹ la (Ẹ fẹ la)
Ẹ fẹ jo (Ẹ fẹ jo)
Ẹ fẹ tikuku (Ẹ fẹ tikuku)
Ẹ ma jo sẹ (Ẹ ma jo sẹ)
Wọn ma la (Wọn ma la)
Wọn ma gbẹsẹ (Wọn ma gbẹsẹ)
Wọn ma tikuku bi ti Poco
Ẹ fẹ la
Ẹ fẹ jo
Ẹ fẹ tikuku
Ẹ ma jo sẹ
[Outro]
Sọ fun wọn k'ọn ṣe jejẹ
K'ọn ma lo f'ori bẹ
Person wey get 2,500 no fit do dorime
(Indomix)
Sọ fun wọn k'ọn ṣe jejẹ
K'ọn ma lo f'ori bẹ
Person wey get 2,500 no fit do dorime
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...