album cover
Amala
album cover
Amala was released on November 9, 2022 by NEVILLE RECORDS as a part of the album Amala - Single
November 9, 2022
LabelNEVILLE RECORDS
BPM
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Music Video

Music Video

Lyrics

[Verse 1]
O ya wait
Pause
Tẹ ba n wa scammer kẹ ma watch
Awa l'eemọ ti o bẹru church
A ṣi ma gbe iya yin wọ Porche
O yọjo
O walẹ
Amọ
Ẹ ṣi maa ka n'lẹ
Gbori bi logo Cowbell
O da pẹ e fori gbalẹ
E sir
Gbori duro
O pe Pepsi ni tuwo
Ma run yin, ẹ ni duro
Ọmọ Ṣibiri to n wegbo
O o mọ mi
O o mọyan
Wa to tẹ, ṣe bo lo stubborn
Do iyawo ẹ pẹlu condom
Awa gan-an-an gan-an-an leyan venom
[Chorus]
Duro nbẹ
A ma la
Awa gan-an-an la ma la
A ma la
Awa gan-an la ma la
A ma run
Emi gan-an mo ma la
A ma la
Awa gan-an la ma la
[Verse 2]
Chinaka, Chikọdị o ni ki n fun n badi nigbati (Your wish is my command)
Iṣẹ yii o si ni church iwọ lo mọ to ba ki n lọ party (Oh Jesus Christ)
Fakafiki ninu okunkun emi ika mo mọ ibi ti n ma sa si (When I am not blind)
Obo japọ mọ furọ ẹ wo ibi a ja si (Koto aye, ladder da?)
Kuo n'bẹ! Nakademus (Nibo?)
Nakamura (Ki lo wi?)
Ninu yara mo ma n dara
Iṣẹ Ọba Solomon, escolopedia
Gbọmu si mi lẹnu ni kekere mummy ni mi o mu feeder
If you call girl for night and you hear switch off
Ma gọ she don dey with us (O ti zeh)
Simply because we dey drop kpa anytime she link up
[Chorus]
Duro n'bẹ
A ma la
Awa gan-an la ma la
A ma la
Awa gan-an la ma la
A ma run
Emi gan-an mo ma la
A ma la
Awa gan-an la ma la
Written by: Abiola Omoniyi Temidayo Raphael, Bisade-Phillips Judah, Ezeh Chisom Faith, Sulaimon Shekoni Abiola
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...