Lyrics

Oba to ku nitori mi, Oba taa pa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi mo mope mi wa fun o Ada lebi iku, kemi le gba idalare Ano ni pasan, kemi maba jiya Oti kikan tomu, kinmaba jekoro ni Atuto si lara, kemi le deni aponle Ikoro irora toje nitori temi ni Oba toku nitori mi, Oba taapa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi, mo mope mi wa fun o La layi jebi ese, asi da lebi eshe Isho owo ati ese re Pelu oko egbe re Iya eshe mi ni Ori ogo lofi dade egun fun emi o Emi o mo oun ti moja mo o Tofi se gbogbo iwonyi Mo mope mi wa Fun Oba to seyi fun mi Oba to ku nitori mi, Oba ta pa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi Odo aguntan to k'eshe mi lo Oloore to gbamila o Ope aanu to po yi, mio riri Mo wa pelu emi imore Oba to di alaini kemi le d'loro Mo mope mi wa fun o Baba Iwo loje kopari Ise ati Iya to tosi mi Iwo loje ko tan aisan ti aarun ti nba ri Iwo logba kokoro iku Ati isa iboji ti nba wo oo Oba to ra iye fun mi Emi mo mope mi wa o oseee Odo aguntan to ko ese mi lo To somi di omo re Mo mope mi wa fun o Oba ayeraye to fi itere sile wa jiya fun emi Mo mope mi wa fun oo Owo elese ni ijoba orun Kole daduro omase Mo mope wa fun o Oro ayeraye to deru nitori mi Mo mope mi wa fun o Iya toje lona agbelebu manigbagbe ni mo mon Mo mope mi wa fun o Oba to laye, to lorun To Wa di alai lara Mo mope mi wa fun o Oobo ogo re kale, owaye wa gbese mi wo ooo Mo mope mi wa fun o Oro ishura ogo iyebiye Lofi fun mi loogun jè Mo mope mi wa fun o Iku E lori igi kafari lofi ra iye fun emi Mo mope mi wa fun o Ori ade ayeraye lofi tegun nitori mi o Mo mope mi wa fun o Emi mo riri ajinde re kemi maba shigbe ni Mo mope mi wa fun o Ore-ofe ti mo rigba lai dinyele loje nmope wa Mo mope mi wa fun o Oun gbogbo tose tose ose fun emi Momope mi wa fun o Bi mo legberun ahon Ko to yin o olupinl'èshè Momope mi wa fun o Alasepe igba gbo Olurapada ore tooto Momope mi wa fun o Momope mi wa f'eni To femi lati odo inu Momope mi wa fun o Oba to feran mi ju enikeni lo ooo Momope mi wa fun o Ore airi oluto okan mi, mogbope ore de Momope mi wa fun o Ope ni mo wa da oo Ope ni mo wa du lodo oloore mi Momope mi wafun o
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out