Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Oriyomi Kehinde Sanni
Oriyomi Kehinde Sanni
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Oriyomi Kehinde Sanni
Oriyomi Kehinde Sanni
Songwriter

Lyrics

Jerryson production Iyawo timoko e lonimoran, oko iyawo tim'aya e lalashiri Kesu mayawon karun mayawon Kiya majewon kondijo barawon gbepe Iyawo timoko e lonimoran Oko iyawo tim'aya e lalashiri Kesu mayawon karun mayawon Kiya majewon kondijo barawon gbe pepepe Toripe Iteriba se pataki kiyawo oni F'ade ori e kosi tun ma bowo fun ni Maroju kojo Maroju koko Maroju koko toko bansoro lowo Je koju tutu kosi rin erin muse Gbiyanju jeyawo toma nwu oko lori Alubarika towa nibe oma kere Kesu mayayin karun mayayin Koshi katayin kedijo gbepo pepepe Iyawo timoko e lonimoran Oko iyawo timaya e lalashiri Kesu mayawon karun mayawon Kiya majewon kondijo b'arawon gbepe MashaAllah Idunnu aya loleto ki oko o wa Taya ba roju ko mona tio gba tujuka Ko f'oriki pe o, koni ashake o Ko f'oriki pe kofeso wo'yawo mora Peloju tutu atoro toro kowipe Ife ayemi honey, idunnu mi darling Iyawo mi kiloun tole fa'runju Toba sepe mose e ni lonfa ibinu Salaye funmi ifemi madimi sinu Kodarijinmi o konisele mo lailai Iyawo timoko e lonimoran Oko iyawo tim'aya e lalashiri Kesu mayawon karun mayawon Kiya majewon kondijo b'arawon gbepe Naam! Toko bapase iyawo gbodo tele ni Toba lo jeyi toti ro poun o ma lese Kiyawo majiyan lesekese si rara Leyin iseju die kosofun oko wipe Ife okan mio Oyin ayemi Olowo orimi moma loro tinfewi Oun teni kase ero kan wa sokan mini Ebaje karo kato gbese si rara Mo mope ooo a bere kilawon lese Kori dajupe imoran tole fun tiwa Oro naa apada wa doro ajoso ni Iyawo timoko e lonimoran Oko iyawo tim'aya e lalashiri Kesu mayawon karun mayawon Kiya majewon kondijo b'arawon gbepe Oko iyawo wa teti gboro tinfewi Teti beleje kole gboro mi yeke Ati feyawo o ja bi okunrin o gbon Mowa foniwa ni loko laya fingbe pe Koma senikan tio nibi towosi Ibi taya kusi koko o mofun loto Ibi toko kusi, kiyawo o mofun loda Kele jogbe dale o, kalafia le joba ni Iyawo timoko e lonimoran Oko iyawo tim'aya e lalashiri K'esu mayawon karun mayawon Kiya majewon kondijo b'arawon gbepe Tor'oju orun funfun nene o labawon o Eniyan se fe dara to koma nibi to wosi Al'oju orun funfun nene o labawon o Eniyan se fe dara to koma nibi to wosi Enife jadun lara oyin oye komope Eni to woyin rebi afara afoju wina o Ise apo kato r'afara gbe wale wa S'oyin to fadun se gbogbo ara t'oyin ba tani Saowa lao ni layinmo aopada la o Toko tiyawo mofe kamo pao serawa o Leyin sorry eje kotan koma ku sinu o Iwa to jowa loje konsope ore jore o Tor'oju orun funfun nene o labawon o Eniyan se fe dara to koma nibi to wosi Eyan mi kan losoro kan funmi nigbakan O nigba toun omai ti feyawo Tawon bajowa pelawon ore to niyawo, telomiran baso nkan tiyawo e se Tawon ba nforo jomitoro oun asope Toun ba feyawo toba dan iru e wo Oun a keru e komalo sile won ni Oloun o mope aimokan nsoun nigbayen ni O l'oun toti juyen lo niyawo oun se Leyin kodija kawon tun pari e ni Tor'oju orun funfun nene o labawon o Eniyan se fe dara to koma nibi to wosi Aimoye oko kiwon nseyawo won Sebawon iyawo won pada mu mora ni Won ni toko awon bati sawon lese kan, kanto bene inu atiro bee naa nio Won ni tori ese gangan l'Olohun seda Aforijin, kaye legun kole n'itura Sale tori ese oko ka lao semo, angeli ko lama rife eyan naa ni Won lawon atoko won timowo arawon, kosiru ese tasewon won mu mora ni Won l'oju orun funfun nene o labawon o Eniyan se fe dara to koma nibi to wosi Asiko yi moti pinnu fun ife mi Latibere tife tayo lafin barase Ifemi ayomi oyin ayemi alashiri mi O gba funmi mose tie denu dokan ni Atijowa moti mo e latana doni o Moti rie tan bosewa bami lara mu Moti pinnu tan lokan mi pe kosi nkan Tole yàwa k'olohun koma fiku yawa K'esu bi eyan ton daleru mayale awa Eniyan sefe dara to koma nibi to wosi Ema delewa mo, ema wale wamo Ija le lewa pari asero ni Abosi lewase o kole gbeyin Anpeyin leyan wa, otete mope, agabangebe lewase atiwa abosi Ede aiyede lani tasi for loyin Oro taso lowuro o koi dirole Ninu adugbo latingbo ateyinkule S'ese ni ka fiyinse eni anforo lo Ija le lewa pari asero ni Ofofo lewa se o kole gbeyin Ao jamo ema wale kan ilekun mo E pase funjalo ao foro loyin Oju aye lewase ayonuso ni Agborodun e japa ao fe riyin mo Ema delewa mo, ema wale wamo Ija le lewa pari asero ni Abosi lewase kole gbeyin Oya o dun o, ofe ke O dun o, ofe ke Untoiiin, ofe ke Oro yen ba oo, ofe ke A bujo, ofe ke A fajo, ofe ke O dun ooo, ofe ke MashaAllah MashaAllah
Writer(s): Oriyomi Kehinde Sanni Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out