album cover
9 Days
album cover
9 Days was released on June 26, 2025 by OCEANSTREET CREATIVE LTD / EMPIRE as a part of the album Prince of the Street
June 26, 2025
LanguageEnglish
BPM151
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Music Video

Music Video

Lyrics

Congratulation l'orin ta maa kọ ọ-ọ
(Decs, motherf-f-f-)
You fit get money make you no get sense o
Gbo-gbo owo ta ma pa, what is the essence o?
Ah, ti n ba ku, ṣe owo le ji mi dide?
Ah, ti n ba ku, ṣe owo le ji mi dide?
Personal vendetta, I've been fighting sapa
Mo ṣiṣẹ, mo ṣiṣẹ, ọmọ oro mi, mo sapa
Ọjọ ti mi kọkọ ri one million, mo sunkun
Alẹ ọjọ yẹn no ni solo ku, mo tun sunkun
On that day, me, I go dey
Ṣe you go dey? Ṣe you go dey?
Congratulation l'orin ta maa kọ
Congratulation l'orin ta maa kọ ọ (ori mi)
Emi lo mi, ẹ gbọmọ lẹyin mi
B'ọmọba n ke, ẹ gbe fun Iya Dada
Miliki yaya, Bournvita yaya
Mi o le ṣe ogun owo
Mi o le ṣe ogun owo
But to ba gb'ọṣẹ fun mi
Mo le wẹ ki n le jo
Olowo ye bi Ọlọrun, calm down
Iwọ kọ lo da mi, o le pa mi
Oble, oble, oble ni mo sọ
Ninu two dollar awọn temi sing along
Aṣabi ṣa dollar, ọmọ owo ṣa pounds
To ba fun mi good strains
Ọmọ, mo ma ra ounce
Olomi, dari ji mi, dari ji mi o
Olomi, dari ji mi, dari ji mi o
Ibadi aran, Mosunmọla, maa ba mi ja ah
On that day, me, I go dey
Ṣe you go dey? Ṣe you go dey?
Congratulation l'orin ta maa kọ
Congratulation l'orin ta maa kọ ọ
Emi lo mi, ẹ gbọmọ lẹyin mi
B'ọmọba n ke, ẹ gbe fun Iya Dada
Miliki yaya, Bournvita yaya
(Motherf-f-f-)
Written by: AYORINDE AYODELE MAFOLUKU, Juju the Pen
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...