album cover
Miscellaneous
1,210
Hip-Hop/Rap
Miscellaneous was released on March 21, 2026 by poshii as a part of the album Lesser Than Zero - EP
album cover
Most Popular
Past 7 Days
00:30 - 00:35
Miscellaneous was discovered most frequently at around 30 seconds into the song during the past week
00:00
00:05
00:30
00:40
00:45
01:05
01:10
01:25
01:30
02:00
02:05
02:10
02:40
00:00
02:56

Credits

PERFORMING ARTISTS
poshii
poshii
Performer
Oluwasegun Ekundayo
Oluwasegun Ekundayo
Vocals
COMPOSITION & LYRICS
Oluwasegun Ekundayo
Oluwasegun Ekundayo
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Oluwasegun Ekundayo
Oluwasegun Ekundayo
Mixing Engineer

Lyrics

Three gbọ'sa fún àwọn brothers mi
Tá n ṣe ọmọ ìyá kan náà
Tá ò jọ sùn sórí bed kan náà, sùgbọ'n a'n lá là kan náà
Ìjọ tí àpò wa rí bákan náà
À n jẹun nínú pot kan náà
À n grind pọ'
À n roll pọ'
À tú gbẹnù sí Cana kan náà
Ó dìgbà tí'n bá blow, kí ẹ tó mọ nkàn ti mo wà capable of
By then, if you ain't gon be my plug baby
Èmi á kà cable love
Mo parọ' love fún Omotoyosi
Just to get puna
Mi ò ní ìrònú'n t'ẹ'mi
If I don see Cana — shikena
Wo broski, mo broke
Gàrí ni mo ń soak
Mi ò ń ṣe introvert, owó ló jẹ' kí n wà lowkey
Pàdì mi, tí ìwọ bá guide díẹ'
Dákùn bẹ'rẹ' AZA mi
Gbà dúrá fún mi, or gbà loan fún mi
Èmi á ṣe amín
Bùh 2k inú Opay mi
Kí n fi tà Tété, o pay mi
Jù kí n send ẹ sí Shaki lọ
Kò wà ní "this money cannot okay me"
Ó gbà mí lágo
Ó fẹ' gbà mí lórí ago
Ó ní send money for come over
Mhm — ọmọgo ló pe mi
•••
Àwọn àgbà bọ', wọ'n dín jìnà
Lọmọ l'ọmọ ń jíbítì, olóṣò tí mo gbé orí mímọ'
Mo lè wà delusional, If delulu is the solulu
Kí n dúró dé time mi?
Nígbà wo ni mo mọ' tí yẹn máa tó lu?
Ayímọ'yé nkan ni ojú mi ti rí
Tí ẹnu mi ò lè sọ
Ayímọ'yé nkan l'ẹnu mi náà ti sọ
Tí ojú mi ò dè rí
Ex mi Valerie, ó ń gbẹnù sí nkan tí ò ní ìdèrí
Kò ń gbé mi trabaye
Kò ń gbé mi dé ibi tí mi ò tíì dé rí
Ó ní preek is unpredictable
Pó dùn bi indomitable
Pé èmi dà bí Man City, I'll always end up on the league table
Owó dè dàbí cutlery tí o lè fi jẹ iṣẹ' anybody
Tí o bá lọ'wọ' lọ'wọ' pàdì mi
Any banny's work is eatable
Írù wa l'ọmọ tí àwọn òbí ẹ a ní kó ṣọ'ra fún, kó má bà á rìn
'Cause we refuse to live by the rules kí ayé wa má boring
À sọ irun di dádá, à lùtì
À n fa huss, à n mútì
À n jàáyé wa, à n Fela
Though Anikulapo, bùh a Kuti
Written by: Oluwasegun Ekundayo
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...