album cover
Ojumi
album cover
Ojumi was released on April 9, 2026 by AAR as a part of the album Beginning of Wisdom (Bow)
April 9, 2026
LabelAAR
BPM104
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Lyrics

Ancestor
Ojú mi á rí’re
Á rí’re
Ah!
Ah!
Èmi tí mo ṣiṣẹ́ ṣiṣẹ́ ni kí n rí’re mú ọ̀ wálé
Làlàkoko fẹ̀fẹ̀ mi
Kí ayé má ṣe lé mi láré
Tí mo bá ń lọ tí mo bá ń bọ̀
Gọngọ á sọ, kutupu á hu, ariwo á ta
Kí orí bá mi ṣé
Kí n rọ́nà gbe gbà o
Ìwọ ni alátiṣe
Kí n rí’re mi gbà o
Ọ̀nà kì ń dí mọ́ ọ̀nà fún ọmọ ọlọ́nà
Fún àwọn aláyọnusọ ẹ ní kó máa yé wọn
Etí mi oh oh
Á gbọ́ ire
(Ire létí agbe ń gbọ́)
(Á gbọ́ ire)
Ojú mi oh oh
Á rí ire
(Ire lójú àṣá ń rí)
(Á rí ire)
Á rí ire, á rí’re
(Á rí ire, á rí’re)
Àwá mà rí ire
Àwá ma rí’re
Àwá mà rí ire gbà
Àwá ma rí’re gbà
Jíjí tí mo jí
Iré bá mi jí
Jíjí tí mo jí
L’ọlá bá mi jí
Wọ́n ń pariwo
Wọ́n ń pariwo lásán
Wọ́n ń pariwo
Pariwo pariwo pariwo
Òní mà a pá
Ọ̀rọ̀ apá kìí ká apá
Igòkègbodò ẹ̀dá láyé
Elédùmarè ló mọ̀
Èmi ọmọ Ajífọlájì fọlàjì
Wọ́n á ní mo tún ń bọ̀ o
Bí iré ṣe wọlé lọ́rùn-ún lósì
Ifá ló ń bá mi ṣọ́ ọ̀nà
Ló ń ṣọ́ ọ̀nà
Ló ń bá mi ṣọ́ ọ̀nà
Etí mi oh oh
Á gbọ́ ire
(Ire létí agbe ń gbọ́)
(Á gbọ́ ire)
Ojú mi oh oh
Á rí ire
(Ire lójú àṣá ń rí)
(Á rí ire)
Á rí ire, á rí’re
(Á rí ire, á rí’re)
Àwá mà rí ire
Àwá ma rí’re
Àwá mà rí ire gbà
Àwá ma rí’re gbà
Etí mi oh oh
Á gbọ́ ire
(Ire létí agbe ń gbọ́)
(Á gbọ́ ire)
Ojú mi oh oh
Á rí ire
(Ire lójú àṣá ń rí)
(Á rí ire)
Á rí ire, á rí’re
(Á rí ire, á rí’re)
Àwá mà rí ire
Àwá ma rí’re
Àwá mà rí ire gbà
Àwá ma rí’re gbà
Wọ́n ní mo tún ń bọ̀
Wọ́n ní mo tún ń bọ̀ wá
Mo tún ti dé
Mo bọ̀ wá
(It's Bizzle on the mix)
Written by: Alexander Abolore Adegbola Akande, Olumide Kayode Awolaja
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...