Lyrics

Mimo l'Oluwa o (mimo) Angeli nwo mike o (mimo) Awon orun nwo mike (mimo) Egbagbeje irawo o (mimo) Mimo l'Oluwa (mimo) Angeli nwo mike o (mimo) Awon orun nwo mike (mimo) Egbagbeje irawo o (mimo) Agbagba merinlelogun (mimo) N'origun merin aye o (mimo) Ati oke, ati ile (mimo) Seri nwo ke o (mimo) Tani yo gori oke Oluwa (mimo) Tabi tani yo duro ni'be o (mimo) Eni ti o ni owo mimo (mimo) Ati aya funfun (mimo) Mimo l'Oluwa (mimo) Mimo o mimo (mimo) Mimo o mimo o mimo (mimo) Mimo o funfun nene ni (mimo) Kabiyesi Eledumare Oba mimo (mimo) Oba la gbogbo aye ete riba fun oba ti oda gbogbo adarihunhun Oba ti oni emi inu eniyan pata Oni kokoro aye l' lowo Adagodo emi gbogbo eniyan Olu kogan orun ajosi edumare Ibinigbi awuwo bi atele Opa tiri kole o ko orun Minimi ojo ti jeki ara odehin Orun wawa ti o pada bo si po Olorun ti o 'so osupa di ale ti oun t' oru Oba ti ose ohun gbogbo ni asiko ni asiko Oba ti ole fi eni 'yi ti, ti a ole fi eyi re ti laila Are la Oba ti eni kan obi, ti obi omo kari gbogbo aye koropodo Olowo ori gbogbo aye pata pata ni Oniwa funfun Oba dake se un ti enikan ole se un si Inu ogo gangan ni oti fo owu Ol' ogo ti oju ogo lo ni Ki abi o ko si Emi o je fi o sere Afi eni ti o ba fe gba query l'odore Mi oje fi oju di o Oba ti ose wo lo ju wo Oti e leti Aledibaje ni o Baba la kun Baba mi Ole gbi yeke Gbogbo eni ti oba mo riri Oluwa Ete riba ewa riri fun Oba nki shi Ibere ati opin Olorun ajanakun ti mi igbo kiji kiji kiji Ti abubu ti a le buto to posi ni gbogbo ojo Eje ka sapa fun Oba rere ti aba mo riri Emi inu awon woli mimo A tobi tan alainiye ko koja kika Terere ko ja riri to Gigun l' alopi Ailetunwo, adawunro, adawunso, adawunse Olulu awon orun, oke la ari owu masiti
Writer(s): Bioku Llc Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out