album cover
Ijoba
album cover
00:00
00:05
00:20
00:30
00:45
00:55
01:15
01:25
01:45
01:55
02:10
00:00
02:19
Past 7 Days
Ijoba was discovered most frequently at around 55 seconds into the song during the past week

Music Video

Music Video

Lyrics

[Intro]
Vado
Naira
[Verse 1]
Ti, ti mo ti gba'jọba
Arọbafin lọba pa
Tani o fẹ tẹriba?
Ka dọbale fun irara o sọ pe ka ma ga (Ka ma ga)
Wọn lo ju ẹ lọ, o lọdun kan pere (Pere)
O sure po ma ni iru ẹ nile (Nile)
To ba jẹ emi ni iwọ, mo ma gba fun
Ọga lọga o ma jẹ, ani o gbe fun
[Verse 2]
Family first money next
Smoke weed, fuck bitches
Get money invest in business
Fake **** impressing bitches
Ṣo gbọ?
To ba lowo, ko tọju ẹbi
Tọju ara ko si tọju ara ẹ
Ma fi ṣeṣekuṣe
T'owo ba pọ, ko ya fi nnkan mulẹ (Mulẹ)
The boy is good, apa lo n jẹ bẹẹ
Wọn ni ko niṣo, pe wọn lẹnu nibẹ (Nibẹ)
Irọ ni wọn kan fẹ da silẹ
T'ọn ba daalẹ, wọn ma fi ẹ silẹ
Hello
Fi ọ silẹ
T'ọn ba daalẹ, wọn ma fi ẹ silẹ
[Chorus]
Awọn l'ọn lẹnu wọn, k'ọn ma rojọ lọ, awa ta ti gba'jọba
People wey fuck with me
Them dey fuck with me heavy, no be for money, ah
Pressure them! Make them see the passion
Make them see hungry man
Anger them! Baba who God don bless nobody fit touch am
[Verse 3]
Dayanmọ ju owo lọ but olowo laye mọ (Olowo laye mọ)
Ka wa ma r'owo na, lọla Anọbi Muhammo (Anọbi Muhammo)
Ki n ma wọ Uber mọ (Uber mọ)
Ki n ma d'olowo ana (Olowo ana)
Today I'm outside my Lord, ki n ma ma ku sọna (Ki n ma ma ku sọna)
Ki n ma ma ku sọna
Ki n ma ma ku sọna, ku sọna
Ki n wọ Al-Jannah
Ninu Al-Jannah (Ninu Al-Jannah)
Saafu deede my friend, lemọmu n bọ (Lemọmu n bọ)
Ọga Ade show your working jọ, I'm done with talk
[Chorus]
Awọn l'ọn lẹnu wọn, k'ọn ma rojọ lọ, awa ta ti gba'jọba
People wey fuck with me
Them dey fuck with me heavy, no be for money, ah
Pressure them! Make them see the passion
Make them see hungry man
Anger them! Baba who God don bless nobody fit touch am
Written by: Anidugbe Oluwatibiloba, Azeez Fashola
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...