album cover
Motide
album cover
00:00
00:10
00:20
00:45
01:00
01:15
01:30
01:35
01:50
02:05
02:10
02:25
00:00
02:30
Past 7 Days
Motide was discovered most frequently at around 45 seconds into the song during the past week

Lyrics

[Intro]
Ọba ti n gb'ẹkun aladura, mo ti de (Mo ti de)
Ọba ti n gb'ẹkun aladura, mo ti de o
Gb'ọrọ mi ro, uh, gbe'ja mi ja
Ma jẹ n gbagbati adura o
[Verse 1]
Ogbigba ti n gba alailara
Ku igba gbogbo mi o
Iba ma ṣe pe mo ni Jesu ni Baba
Ọmọ araiye o ba joju mi
Eniyan sare ko le bajẹ ṣugbọn o, ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi
[Verse 2]
Ọmọ, ṣe you know aanu ni mo ri gba lọdọ Yahweh?
O fun ọmọ araye laye lati bere pe "Ọlọrun mi da?"
Mo yege
Ori mi san're, adura mi gba (Oh-ah)
When I call Am, He dey answer
Ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi
[Chorus]
Ọba ti n gb'ẹkun aladura, mo ti de
Ọba ti n gb'ẹkun aladura, mo ti de o
Gb'ọrọ mi ro, uh, gbe'ja mi ja
Ma jẹ n gbagbati adura o
Yea-yea, yea, yea-yea
[Chorus]
Ọba ti n gb'ẹkun aladura, mo de, sẹ
Ọba ti n gb'ẹkun aladura, mo ti de o
Gb'ọrọ mi ro, oh, gbe'ja mi ja
Ma jẹ n gbagbati adura o
[Verse 3]
Who can ta'ku laya?
Nobody, ta lo fẹ gbe'ra ẹ si
Nobody reach to question You
You know You be the final say, kabiyesi o
Oh! When I had no one to call on
Ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi
[Verse 4]
Ọmọ, ṣe you know aanu ni mo ri gba lọdọ Yahweh?
O fun ọmọ araye laye lati bere pe "Ọlọrun mi da?"
Mo yege
Ori mi san're, adura mi gba
When I call Am, He dey answer
Ẹjẹ Rẹ ṣeun fun mi
[Outro]
(Sunshine)
Written by: Oluwakayode Qudus balogun
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...