Credits

PERFORMING ARTISTS
Brymo
Brymo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olawale Ashimi
Olawale Ashimi
Songwriter

Lyrics

[Verse 1]
Ni kekere, a ma n ṣere
A ma n fawọn agbaagba ṣere, a ma n mere
Iya Dele
Sọ fun Dele
Ko ye fona, ko to wọna, ko to mere
Bọmọde n ṣere
Ko to ṣere dele
Awọn agbaagba wọn ma ṣeto werewere
Bọmọde n ṣiṣẹ
Ko to rijẹ
Itiju ni fun awọn agbaagba to ran an niṣẹ
[Chorus]
Jẹle o sinmi oh
Jẹle o sinmi
Jẹ kọmọde o kawe
Ko kẹkọọ jere
Jẹle o sinmi oh
Jẹle o sinmi
Awọn agbaagba mura siṣẹ werewere
[Verse 2]
A ma n ṣere
A ma n sare
A ma n ṣubu, a ma n dide, a ma n dele
Iya Taye
Sọ fun Taye
Ko ye sọrọ, ko to mọrọ yekeyeke
[Verse 3]
Kọmọ o to sa n'le
Ko to di pe o n sare kiri
Awọn agbaagba wọn ma ṣeto werewere
Bọmọde n ṣiṣẹ
Ah, ko to rijẹ
Itiju ni fun awọn agbaagba to ran an niṣẹ
[Chorus]
Jẹle o sinmi oh
Jẹle o sinmi
Jẹ kọmọde o kawe
Ko kẹkọọ jere
Jẹle o sinmi oh
Ko sinmi
Awọn agbaagba mura siṣẹ werewere
[Chorus]
Jẹle o sinmi
Ko sinmi
Kọmọde o kawe
Ko jere
Jẹle o sinmi oh
Ko sinmi
Awọn agbaagba mura siṣẹ werewere
[Outro]
Ko sinmi
Ani ko sinmi
Ko kawe
Ko jere
Jẹle o sinmi oh
Ko sinmi
Ko, ko sinmi, ko jere
Written by: Olawale Ashimi
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...