Şarkı sözleri

Iwo lo ye Ogo Ola Iwo lo ye Iyin Eeye (Iwo loye o) Iwo lo ye Ogo Ola Iwo lo ye Iyin Eye Iwo l'ope to si Oba mimo Iwo niyin to si Oba toto Ikawo Re Lohun gbogbo ti wa Iwo lo ye Ogo Ola Iwo lo ye Iyin Eye Iwo lo ye Ogo Ola Iwo lo ye Iyin Eye Iwo l'ope to si Oba mimo Iwo niyin to si Oba toto Ikawo Re Lohun gbogbo ti wa Iwo lo ye Ogo Ola Iwo lo ye Iyin Eye Kabiyesi o Eledumare To to to Oba Kabiyesi o Oba to joko lori obiri aye Ogo fooko Re To to to Oba Iba Re Iba Re to to to To to to Oba To to to Oba Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo To to to Oba Kabiyesi o, awon orun n soro ogo Re, ofurufu n fise Re han To to to Oba Ise Re po gaan ni ko lafiwe o, a wole a fiyin foruko mimo Re To to to Oba Kabiyesi o, Baba mi, Olorun mi, Eni to lebun gbogbo To to to Oba Iba Re, iba, iba, to to To to to Oba To to to Oba Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo To to to Oba Oba Ibere Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo To to to Oba Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Baba to lemi mi ogo fooko Re Iwo ni Baba to ju baba lo Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Alagbara kan ko ma si Onimo kan ko ma ma si o Ko si o o o Ko si leyin Re Iwo l'Oba to lemi mi Iwo ni Iwo saa ni maa fi gbogbo igba mi gbe ga o Ko selomiran leyin Re Ko si o Ninu aso igunwa t'O fi se mi loso mo ba ruburubu Mo foribale fooko Re o Iwo saa ni Ologbon julo Ko si o (ko si o) Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo A se ite fun O ninu okan wa Iwo ni Iwo ni Baba to ju baba lo Inu orin iyin awon eni mimo niwo n gbe Baba Iwo ni Baba to ju baba lo Oba to joko lori ite, awon angeli n foribale fun O Iwo ni Baba to ju Baba lo (Eyin ni) Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Eyin ni Baba to to baba Eyin ni Baba to ju baba lo Eeeh e wa, e wa woran o Baba wa ni E wa w'Alewilese o Baba wa ni Alagbawi awa o Baba wa ni Oba to tan 'mole sona wa, Oun ni Baba wa ni Aye si n be, elese wole wa Baba wa ni Baba wa po ni agbara, O po ni aanu o Baba wa ni Eh eh eh ah e lo simi agbaja Awa ni Baba kan to moye Oun lo tun le aye awa se ge ge Eh eh eh eh eh eh ah Eh eh eh ah e lo simi agbaja Awa ni Baba kan to moye Oun lo tun le aye awa se ge ge Eh e wa e wa woran o Baba wa ni E wa wo Olurapada Alaanu to n tu ni sile Baba wa ni E wa wo Alara ire Oba to n tun ni se Baba wa ni Eni to wa leyin ogba ko wole wa Baba wa ni Aye si n be ninu ogba Alaanu o Baba wa ni B'omode sun, a fi isori E so Baba wa sun, a fi isori E so Ire la mo t'O n gba wa lowo ewu Hallelujah Ogo ni fun Baba Ki la fi san j'awon t'iku ti pa Ire lo s'aabo, alaafia wa Ire la mo t'O n gba wa lowo ewu Hallelujah Ogo ni fun Baba Oh oh oh oh Allelu... Hallelujah Ogo ni fun Baba A ti ri 'gbala ojo oni Alaaye ni yoo yin O bo ti ye Hallelujah Ogo ni fun Baba A a a a a a allelu... Hallelujah Ogo ni fun Baba A fijo filu yin Olorun wa Alaaye ni yoo yin O bo ti ye Hallelujah Ogo Oluwa ooo Eh eh Oluwa ooo Eh eh Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa eeeh Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa Ope ye O ooo eh Ope Eni to joko lori ite ogo fooko Re Ope Ope ye O ooo eh Ope Ope ye O ooo eh Ope Ope ye oruko Re Iwo nikan ni Ope Ko si o Tani n ba sin bi o se 'Wo Oba to f'aanu tan 'mole sona mi Ko s'elomii leyin Re Orin yi naa ni emi o maa ko Orin irapada imole t'O tan fun mi Aanu n mo ri gba, ookun pada di'mole lona mi Ko si leyin Re Ajoda ope la da Iyin sa la mu wa Ajoda ope ni gbogbo iseda da Iyin sa la mu wa F'Oba to Lola Olu sola to fun ni lola se Olupenisola Ogbenuenisola Ta lo le sola Lai se p'Oo fun lola se Ola Re lo n fun ni lola T'aa fi n sola ninu Re F'Oba to fun ni lai gbebo o Ope la mu wa Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Alagbara kan ko ma si Onimo kan ko ma ma si o o o o Ko si ooo Ko si leyin Re Iwo ni ma ma yin lojojumo Iwo ni maa fi aye mi gbega o Ko selomiran leyin Re Ko si o eeee Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re Ko si o Ko si o Ko si o Ko si leyin Re
Writer(s): Sola Allyson Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out