音樂影片

音樂影片

積分

演出藝人
Sola Allyson
Sola Allyson
演出者
詞曲
Sola Allyson
Sola Allyson
作曲
製作與工程團隊
Sola Allyson
Sola Allyson
製作人

歌詞

[Verse 1]
Wá wọlé
Máa bọ̀ ọmọ
Ọ̀nà ìmọ́lẹ̀ yii mà ń pè ni
Wá jẹ nínú adùn yẹn o
Wá wọlé
Máa bọ̀ ọmọ
Ọ̀nà ìmọ́lẹ̀ yii mà dùn gan-an
Wá jẹ nínú adùn yẹn o
Wá wọlé
Kòs'ádùn l'óde
Máa bọ̀ ọmọ
Ibí l'adùn wà ọmọ
Wá jẹ nínú adùn yẹn o
Wá wọlé
Come come máa bọ̀ ọmọ
Ọ̀nà ìmọ́lẹ̀ yí mà dùn gan-an
Wá jẹ adùn yẹn o
[Verse 2]
Gbà mí gbọ́ p'ọdún yí á sàn wá
P'ọdún yí á sàn wá
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'ọdún yí á sàn wá
P'ọdún yí á sàn wá
[Verse 3]
Gbà mí gbọ́ p'ọdún yí á sàn wá o
Ìgbé ayé tí mò ń gbé á sàn mí o
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'ọdún yí á sàn wá
P'ọdún yí á sàn wá
[Verse 4]
Gbà mí gbọ́ ayé yí á sàn mí o
Ayé è yí á sàn wá o
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'ọdún yí á sàn wá
P'ọdún yí á sàn wá
[Verse 5]
Gbà mí gbọ́ ọdún yí á sàn wá
Ayé tí mo ń gbé á sàn mí o
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'ọdún yí á sàn wá
P'ọdún yí á sàn wá
[Verse 6]
Gbà mí gbọ́ aláyọ̀ m'áyọ̀ dé o
Aláyọ̀ ọ́ m'áyọ̀ dé o
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'aláyọ̀ m'áyọ̀ dé
Aláyọ̀ ọ́ m'áyọ̀ dé
[Verse 7]
Gbà mí gbọ́ bàbá aláyọ̀ m'áyọ̀ dé sínú ìbànújẹ̀ ọkàn mi
Aláyọ̀ m'áyọ̀ dé o
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'aláyọ̀ m'áyọ̀ dé
Aláyọ̀ ọ́ m'áyọ̀ dé
[Verse 8]
Gbà mí gbọ́ aláyọ̀ ma ṣ'ògo
Aláyọ̀ ma ṣ'ògo
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'aláyọ̀ ma ṣ'ògo
Aláyọ̀ ma ṣ'ògo
[Verse 9]
Gbà mí gbọ́ bàbá ológo a fi mí ṣ'ògo
Aláyọ̀ máa ṣ' ògò
Gbà mí gbọ́
Gbà mí gbọ́ p'aláyọ̀ ma ṣ'ògo
Aláyọ̀ ma ṣ'ògo
[PreChorus]
Bàbá rẹ l'ó l'ọ̀rọ̀
Bàbá rẹ l'ó l'oore gbogbo
Bàbá rẹ l'ó ní ògo
Bàbá rẹ l'ó ni ọ̀rọ̀
Bàbá rẹ l'ó l'oore gbogbo
Bàbá rẹ l'ó ní ògo
[Chorus]
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má ṣ'ojo
Ọm'ọba má gbàgbé o
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má ṣ'ojo
Ọm'ọba má gbàgbé o
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má ṣ'ojo
Ọm'ọba má gbàgbé o
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má ṣ'ojo
Iṣẹ́ t'á a rán mí sí ọ nìyẹn
Ọm'ọba má gbàgbé o
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má ṣ'ojo
Ọm'ọba má gbàgbé o
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má mi'kàn
Ọm'ọba má ṣ'ojo
Ọm'ọba má gbàgbé o
Written by: Sola Allyson
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...