積分
演出藝人
Ogo Akin-Alade
電子低音吉他
Prince Shegs Adeh
吉他
詞曲
Tope Alabi
詞曲創作
Akinade Ibuoye
詞曲創作
Philips Oyewole
詞曲創作
製作與工程團隊
Tbabz
製作人
Prince Shegs Adeh
製作人
Monaze
製作人
Mikkyme Joses
混音師
464 StudiosLagos Nigeria
錄音師
歌詞
[Chorus]
Particularly o, particularly o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
Undoubtedly o, unquestionably o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
[Verse 1]
Ain't nobody like my Daddy
Just taste and you will see
O ya take this as an IV
You can come and join our family
Whether dem like am or dem no like
Eventually every knee will bow
And so, if I were you, I'll proclaim Jesus now
To live is Christ, to die is gain
So I live my life to proclaim Your name
And when my time on earth is done
My highest pride is to hear "Well done" from You o
[PreChorus]
So I bow to no one, I bow to no one but You o
Cos my life is all Yours, my life is all Yours o, my Daddy o
[Chorus]
Particularly o, particularly o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
Undoubtedly o, unquestionably o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
[Verse 2]
Ifẹ agbelebu lo dun ju o
O ba mi lara mu gan-an ni, o ba mi lẹjẹ mu
Ọmọ ẹya ba bi, ẹya ni yoo jọ jare
Oke oku loku n re, Baba ọmọ lo lọmọ ẹ
Oun lo fẹ mi yan lati ibi agbari, Golgotha ibi ifẹ
Ko sẹni to le gba kẹnbo lọwọ imu
Unapologetically, Ẹni to laye mi ni ma a ba lọ
To r'onirese to fingba aye mi ni o
[Chorus]
Particularly o, particularly o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
Mo ti ba lọ, mo ti ba lọ, mo ti ba lọ, oh
Undoubtedly o, unquestionably o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
[Chorus]
Particularly o, particularly o
Ẹyin ni lọjọ gbogbo
Ṣẹ mọ pe bolode o ba ku orita wọn ki i hu gbẹgi
Undoubtedly o, unquestionably o
Ẹyin ni l'ojo gbogbo
[Outro]
Iwọ o dẹ le ku lailai
Aiku ni Ọ o, Baa mi
Written by: Akinade Ibuoye, Philips Oyewole, Tope Alabi