Lyrics

Awon adan fo loke Won foka si oju orun Won o ma mo ibi won lo Eledua lo n shey ike won Ko keyin si é, oré o O hun o n wa O wa ni waju re Adedotun— Oyindamola mi Ero gbogbo e ba gberin Adedotun o Awon adan fo loke Ni igba, igba Won kun oju orun Won o ma mo iwun wan n je Eledua lo n sho won Lo n bo wan Ko pamo si é Oré ooooooo O wa lo Sokoto O wa lapo sokoto Adedotun Oyindamola mi Ero gbogbo e ba ngberin Adedotun o Adedotun Oyindamola mi Ero gbogbo e ba ngberin Adedotun o Ko pamo si é Oré ooooooo O hun o n wa O wa ni waju re o
Writer(s): Olawale Olofo'ro Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out