album cover
Aare
9,931
World
Aare was released on July 6, 2018 by YBBM as a part of the album Aare - Single
album cover
Release DateJuly 6, 2018
LabelYBBM
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM125

Music Video

Music Video

Credits

Lyrics

Lo'gun ọfẹ
Ahoo! (Lo'gun ọfẹ)
O de o (lo'gun ọfẹ)
Ọmọ imalẹ afeleja
(Lo'gun ọfẹ, lo'gun ọfẹ, lo'gun ọfẹ)
Qdot l'orukọ mi
Irukẹrẹ ọba le ma si lọwọ mii
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọwọ mii
Mi o b'anybody ja s'ọba, ah-ah-ah
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọwọ mii (Aare Ọna Kakanfo)
Ẹ bun mi lọwọ mi (Aare Ọna Kakanfo)
Jagunjagun ni mi, ẹ ma ri mi fin (Aare Ọna Kakanfo)
Akinkanju ọkunrin loju ogun (Aare Ọna Kakanfo)
Wèrèpè oni'bikan ta maa gba mu (Aare Ọna Kakanfo)
Ma lọ di mu, ko ma di'na mu (Aare Ọna Kakanfo)
Awọn ọmọ Oduduwa mi o fi mi ṣere (Aare Ọna Kakanfo)
I deserve some accolades (Aare Ọna Kakanfo)
Yeah-yeah, yeah-yeah
Ẹ duro na, kẹ jẹ n sọrọ
Ẹ jẹ n sọ t'ẹnu mii
Wọn d'ohun m'agogo lẹnu
Tori kuku luku s'ewe gẹlu gẹlu
Tori a f'aja ṣọ'le
Aja p'oun l'ọba ẹkun
Ara me riri, mo r'emọ, ki lo fa t'alantakun l'eri s'alabahun?
If you don't like me, I don't like you
Forget the Yorùbá I spoke o
Ma p'agbada fun mi ni raincoat o
Mo ti jẹlọ ọ, ko s'ohun tẹ fẹ ṣe
K'aṣẹwo to ko pẹtẹsi, oju ri
Ẹ sọ f'ologini to f'oju d'ẹku
Ko mọ'ru ẹranko to maa ba ta'hun ni igbọ
Irukẹrẹ ọba le ma si lọwọ mii
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọ'wọ' mii
Mi o b'anybody ja s'ọba, ah-ah-ah
(Lo'gun ọfẹ, lo'gun ọfẹ)
Tẹ ba ti ri mi, kẹ fun mi lọwọ mii (Aare Ọna Kakanfo)
Ẹ bun mi lọwọ mi (Aare Ọna Kakanfo)
Jagunjagun ni mi, ẹ ma ri mi fin (Aare Ọna Kakanfo)
Akinkanju ọkunrin loju ogun (Aare Ọna Kakanfo)
Wèrèpè oni'bikan ta maa gba mu (Aare Ọna Kakanfo)
Ma lọ di mu, ko ma di'na mu (Aare Ọna Kakanfo)
Awọn ọmọ Oduduwa mi o fi mi ṣere (Aare Ọna Kakanfo)
I deserve some accolades (Aare Ọna Kakanfo)
Yeah-yeah, yeah-yeah
Ti ko ba ni idi, a ki n r'ẹja loke odo
T'ọwọ ba ti gb'owo ẹyin, ẹnu o ni le s'ododo
Before, before, I dey do like mumu for dem
Ay, dem dey do face like a Lion
Fẹlẹfẹlẹ ni wọn bi ti nylon
Yiyọ ẹkun t'ojo kọ
Ẹ maa f'ẹkọ ta'na fun mi jẹ
Kanakana ko ma na ọmọ ẹga
Agbado inu'go f'adiyẹ, awomọju ni
T'omi o ba to la ti wẹ, a fi bọ'ju ni
Don't feed me what I don't eat
The fall of a dry leaf, it's a lesson for the fresh one
Lo'gun ọfẹ o, lo'gun ọfẹ ẹ (k'ara o le, baba)
Aare. Ganiyu Ige Adams
The 15th Aare Ọna Kakanfo fun gbogbo Ile Yorùbá
Jagunjagun f'awọn Yorùbá (Aare Ọna Kakanfo)
Ooni of Ife, Alaṣẹ igbakeji Orisa (Aare Ọna Kakanfo)
Ọjaja Keji, Arole Oodua (Aare Ọna Kakanfo)
Mo mọ Alaafin Ọyọ (Aare Ọna Kakanfo)
Iku baba Yeye, iku to n pa ku jẹ (Aare Ọna Kakanfo)
Mo ki ijoye, Mo ki gbogbo Ọba Alade o (Aare Ọna Kakanfo)
Gbogbo ọmọ Yorùbá n'ile, l'aajo (Aare Ọna Kakanfo)
IBD Dende (Aare Ọna Kakanfo)
Arẹmọ Oni'ru, Akin Shittu olori Ẹyọ (Aare Ọna Kakanfo)
Fẹmi Jaguar, Shina Peller (Aare Ọna Kakanfo)
Fuad Olotọ, Laolu Selfmade (Aare Ọna Kakanfo)
Sir Kuti kogbadigi, Billy Q, El-Dubai (Climax)
Oluọmọ f'Ọlagbade wa ni Bangla rẹ (Aare Ọna Kakanfo)
Sir K, Ọlọruntoyin ni Bombay (Aare Ọna Kakanfo)
Taiyeolu fo ni Toronto oo
Qdot l'orukọ mi ooo
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...