album cover
Idan
7,652
African
Idan was released on May 27, 2023 by YBBM as a part of the album Idan - Single
album cover
Release DateMay 27, 2023
LabelYBBM
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM125

Credits

PERFORMING ARTISTS
Qdot
Qdot
Performer
PRODUCTION & ENGINEERING
2tupondeebeatz
2tupondeebeatz
Producer

Lyrics

[Intro]
Qudusi idán
Idán gangan, idán
Ọmọ Mọriamọ, idán (Idán o-o)
Qdot l'orúkọ mí
[Verse 1]
Wọn mò pé emi ni idán (Idán)
Idán tí ó wẹ tó ń dán (Idán)
Qudusi idán (Idán)
Idánkídàn (Idán)
Báwo l'áyán Lekki ṣé ń dan? (Idán)
Àdánwò o ki ń ṣe ọrẹ idán (Idán)
Gbowó lọwọ Palmpay (Idán)
Ko fi sanwó Opay (Idán)
Idán o gbọdọ sùn (Idán)
Tori Yankee o ni pẹ ji (Idán)
Owó olówó l'égún na (Idán)
Ootọ ni Peller ń pádan (Idán)
Obesere lóhùn lọba idán ṣugbọn, idán gan-an gan-an lo n ju idán (Idán)
Oùn lo mu Sọdiki ọgbọn gan-an lọ gbà arodan fún dan (Idán)
Ẹ wọnmi si itan omidan (Idán)
Kẹ to gbétan letan (Idán)
Ẹ ma jẹdan mọdan ki idán ma ṣẹrù fún omidan (Idán)
Idán wey slap popo (Idán)
Idán no dey sleep na sleep dey wait for idán (Idán)
Idán ò ní wówó kiri owó ló má ń wa 'dán (Idán)
Idán na him be the don na why idán dey sit down (Idán)
[Verse 2]
Alhamdulillah, mo mọpé ẹ ti jẹyẹn tán (Idán)
Ọlá Olùwà o kí n tán (Idán)
Lamba mi o le tán (Idán)
Kàkà ki idán jabọ sí kòtò mọnamọna ma tàn (Idán)
Idán na don (Idán)
Idán na high don (Idán)
Don Jazzy gan bẹrù Idán (Idán)
Wọle Soyinka ti o bẹru idán ni ori ẹ ma dán (Idán)
Adan bi t'ogidan (Idán)
[Verse 3]
New Edition, idán (Idán)
Fẹnu rodan (Idán)
Fẹnu wù igi odán (Idán)
Ma ba wọn fẹnu lu gángan, ma wo ojú ko tọ fẹnu jù 'dan (Idán)
Idán ju 'dan lọ (Idán)
Loni yan-yan, yan-yan, yan o lè sọrọ, online lo wa (Idán)
Chicken, ò lè fò bi ẹyẹ àdán (Idán)
Eku ni ifá ń jẹ (Idán)
Adífá lo n jẹ màlúù (Idán)
Idán no be yahoo (Idán)
Idán to ń dàn (Idán)
From Bourdilon to Aso Rock (Idán)
Jagabanu ní Idán (Idán)
[Verse 4]
Mo mọ awọn idán gangan
IBD Dende, idán
Ọmọ Egungbohun, idán
Ṣeyi Tinubu, idán
Baddy Osha idán
Lanre Typical, idán
Kosi idán kàn to n tá mọto lẹyìn Arowolo, idán
MC Oluọmọ, idán
Riliwanu Cooler, idán
Ọba Sheffield, idán
Kunle Poly, idán
Tafa Sego, idán
Kazeemu Elesu, idán
Kapa Owoẹyẹ, idán
Ọkanlọmọ, idán
Ajibola Pasuma, idán
Mo mọ Fẹmi Joro
Mo mọ Fẹmi Jaguar
Abu Abel, idán
Sammy Larry, idán
Tarry Shiny, idán
Anọbi tiwa ni Mushin
Mo mọ Lawali l'Abuja
Mo ṣe ibà Oníbà of Ibà
Billique, idán
Maverick, idán
Doctor Brown, idán
Bobrito, idán
Mo mọ Wale ticket
Kazzy lo fi idán sí mọto
Eniola Tizzle, idán
Ọlọfin Snipper, idán
Ẹgbọn mi Bunmi Obakoya, Tunla of Lagos, idán
Mo mọ Bishop nílùu Turkey
Mo mọ Dandy, mo mọ Otunba Kashy
Ọmọ Ayilara mi, ọrọ pọ Ọmọba Kumasi
Ikorodu wa, say boko, Alabi Spatarcuz
Baba Rado
[Outro]
Qdot l'orukọ mi
2T upon the popo o-o
(2T on the mix)
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...