Listen to BREAKFAST by Qdot

BREAKFAST

Qdot

African

8,358 Shazams

Lyrics

(Lílù) Alágbe (Shocker lo ṣe beat) Onílù yí jọ- oo Ọmọ ẹluku mẹdẹ-mẹdẹ, ìmolè àfelẹja Emi naní, ọmọ-ọmọ Moriamo Qdot l'orúkọ kọ mí Wọni oro dákun mà soko, ẹjẹ ńsọ tọwọ mí náà Ẹdakún, níbo lo wa, nígbà tí mo fojú wina? Mo badi, ìmolè ní mí Òyìnbó odún lẹnu mí, torí Ìbílẹ ní mí Tẹ ba ní ké mú ẹnì àf'ọlá Labalaba tó ṣẹré ẹ̀gún, aṣọ rẹ mafaya I'm here for the money, not the fame Ask about me, I'm making money in the game B'ologiní bà gún orí ajá, àrí'lé àrọko Fuck anybody fuckable, I don't care Mo dá bí Messi, mo dá bí C'Ronaldo Mo mọ Sanwo Ayanlu, ẹruku mo bá tó Lalude gàn o'lẹ p'Abija Ọmọ Ìbàdàn tó f'èwe sẹnu, ṣọ'le Bodija? Ẹtakete, berí mí ní orítá Molete, emí kó lé má challenge Moda, (moda gan) Àta ní mí, motá (mota gan) Ìná mí o mẹní tó da, werepe ní mí, ẹma loja (Alagbe sọrọ) Award onigi, iná ìgi lama fí dá Fuck your lyrics, he's on the road, I'm the best Tába tí àdà, fún àwọn tìwá wọn o dá Wọni wọn ogbọmí, speaker wọn ní o dá Mí o need akaba, kí ńto ga t'àlaga Ká dobalè fún àrá, ìyẹn o ní kamá ga Punchline fọ wọn lẹ'nu lọ gba-gba-gba Ẹsẹ' May Weather mo gbéwá Dákun, mà lọ faya gbà Ayangba dangerous Makinde pá'wó ju Linda Ikeji lọ Ẹma pá ohùn má gogo, ẹjẹ ń polongo Ẹṣù lo lorita, Oluweri lo lodò Don't near me, I'm bad Ọmọ àke nígbo, keru bá àrá ọna Ọmọ má jegi jẹ èniyàn, oríkì Bàbá mí ní Oka mí lará gàn, o'sho jù Abu Abel Ṣebi ká rín, kápọ, yíyẹ ní ńyẹni Ko dẹ ní yẹ yín, ewúré lo má gbà ògo yín Boku ọwọ kàn àdán, àdán má fí rogi Kólé burú títí, kí ọmọ àlapatá mí wá jegi Wọn wípé mariwo larí, pe'égún ńbọ Nígbà tẹ'gún rí wá gàn, eégún gbọn Ẹdakún, ṣẹ'ẹyẹ àdán ní (àbí) ẹiyẹ guungún? Wọni àwọn m'ẹyẹ lápo, ẹiyẹ tún tí kú Bà rán niṣẹ ẹru, àmà fí tọmọ jẹ Bàbálawo tí o já, lomá padà toro jẹ Bí ìṣe kàn o lomọ, ìṣẹ kàn lo ńlọ Tí o bá jawó lo rí dating, gbé sórí PPP Wọni, Acapella rẹ dùn, ìwọ dákun má fí ìlù sí (Shocker lo ṣe beat) Saladi mí, lọ fẹ bámí fí ìru sí Ogún tí o jẹ, ṣẹ bí ẹwé ẹ loku kàn Ọba ní mí Alagbe o rẹ bí kán-kán Kabiesi o (kabiesi o, kabiesi o) (yeah, who's here?) Ọmọ Àjànà
Writer(s): Fakoya Oluwadamilare, Mudashiru Olajide Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out