Music Video
Music Video
Credits
PERFORMING ARTISTS
Tope Alabi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Patricia Temitope Alabi
Songwriter
Lyrics
[Verse 1]
Alaabo to peye oun lo n gbe mi ro titi di iwọyi o eh
Oore ọfẹ ti mo n jẹ aanu yẹn pọ lo mu mi yan falala
Babara loore to mu mi ji to mu mi sun mo gbọpẹ oore de
Aramanda loore ti mo le gbapa ti mo le gbẹsẹ mo la ju mo fi ri
Ọtọ loore pe mo le jẹ mo le mu wọn o f'ounjẹ nu mi o
Aanu loore pe kemi jade ki n wọle alaafia ni
[Verse 2]
So when I put together
Oore to ṣe laye mi
Yet none stop
Mo mọpẹ wa
So when I put together
Oore to se laye mi
Yet none stop
Mo m'ope wa
[Chorus]
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ, o ṣeun
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ, o ṣeun
[Verse 3]
O ya mi lẹnu, o jọ mi loju
O ka mi laya mi o riru ẹ ri
Wọn wa n beere lọwọ mi
Ewo ni mo tọla, ewo ni mo jẹ?
Ṣ'emi tọrọ o ye rara ni ma ṣalaye
[Verse 4]
Baba lo n do that thing for me
Mo ma raanu gba ni
Tani iba mokolo mi tẹlẹ
Aanu gbaye mi wọ ni, mo moore
[Chorus]
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ, o ṣeun
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ, o ṣeun
[Verse 5]
Wọn beere b'omi ṣe denu agbọn
Ijilẹ lo jẹ ko sẹni to ye
Wọn fẹ mọ boore ṣe pọ lara ọpẹ
Ko dẹ le ye anybody
Aṣiri ninu Eledumare ni
Baba lo n gbeṣe ọwọ rẹ gbara
Lemi ṣe n gbohun ọpẹ mi soke o
Oun lo n f'aye mi ṣe glamour
Lemi ṣe n mọpẹ igba gbogbo mi wa
He's one doing that thing
[Chorus]
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ, o ṣeun
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ
Iwọ lo n do that thing for me
Ti mo fi n dupẹ lọjọọjọ, o ṣeun
[Verse 6]
Jesu tigbesoke wa n bẹ lọwọ rẹ
A gbe ọ ga o, a gbe ọ ga
Kristi tigbesoke wa n bẹ lọwọ rẹ
A gbe ọ ga o, Ọlọrun ifẹ
Iwọ tigbesoke wa n bẹ lọwọ rẹ
A gbe ọ ga o, a gbe ọ ga
Iwọ tigbesoke wa n bẹ lọwọ rẹ
A gbe ọ ga o, Ọlọrun ifẹ
Ani tigbesoke wa n bẹ lọwọ rẹ
A gbe ọ ga o, a gbe ọ ga
Iwọ tigbesoke wa n bẹ lọwọ rẹ
Mo gbe ọ ga o
O ṣe Olodumare o
Written by: Patricia Temitope Alabi