Lyrics

Adake dajo On lo mo wa o, O mi wo wa w'okan Ohun gbogbo ti a gb'aye se On lo da ojiji mo wa o Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w'okan Ohun gbogbo ti a gb'aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro Eni to da oju o, ko ni s'alairiran Olu to da eti o, ko le s'alaigboran Ko si koro loju Re, gbangba kedere lo ri gbogbo wa Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w'okan Ohun gbogbo ti a gb'aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro K'a ye s'esin, k'a ye pe e ni esin, k'a lo ja'wo pata A o le gan Olorun pelu 'gbagbo oju tori ko ni le gba wa A n fi ti'pa gboran si 'lana esin, ofin Olorun wa d'afieyin Opo dara loju, iwa won o dokan T'egbin t'idoti ko je k'adura opo onigbagbo o gba Ojiji t'Eleda da mo wa, o n s'afihan ohun ikoko o E o ni le gba'bode f'Olorun, onitohun a wule tan 'ra e pa Olorun alawopa, dakun ma wo mi pa Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w'okan Ohun gbogbo ti a gb'aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro Eemo to wo 'jo Olorun ti wa bureke, gbogbo aye di 'ranse Olorun At'eni Baba ran, at'eni ebi le de Woli osan gangan, iyen lo bi rere Ori pepe di 'gbale egungun At'alafose at'elepe Ogo ologo de ku t'on mi wo s'agbara Igbadi m be labe collar opo won Awon t'ogun nja t'on tori k'ogun o le se t'on wo 'nu ijo wa O ma se arakun laso gbagi logun to n kun ogun won Ab'e o ri ijo, ki Jesu to de ki ni yio da o Adake dajo On lo mo wa o, O n wo wa w'okan Ohun gbogbo ti a gb'aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at'opin re, O ri gbogbo koro E je k'a bi 'ra wa leere, gbogbo iranse Olorun pata Kini idahun si ibeere yi o Oro ijoba orun ti di 'waasu igbaani lenu wa Ere wo lonisowo agba n je ninu ise wa E gbo ere wo, ere wo, lOluwa n je A fowoleran O ma n wo wa o Ko ma ka 'se mi lai lere kankan Ki loo ro, ki loo so Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Ki loo ro, ki loo so Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so T'a ba p'oruko ni'joba orun T'a pe won titi ti o de kan e o Eni to n toka s'omo apaadi, at'eyin to mo 'mo ile ologo T'on ba p'oruko ni'joba orun, t'on o ka mr census e ki loo ro Ki loo ro, ki loo so Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Onigbagbo ka ri mi ete eke Lati inu ijo je 'ra wa lese dede Adura at'aawe odi s'enikeji Ife ikoko lori pepe si pepe E o ranti O da ogbon o ju ogbon lo E o ba lako bi ibon lese-o-gbeji Ki loo ro, ki loo so Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Ojo nla, Adajo aye fere de Aiyiwapada idajo a ro K'onikaluku lo ye 'ra e wo Ibi t'o ba ku si, gb'adura k'o tun se Ko ma ba di ki loo ro K'enu ma wo ji, ailesoro Ki loo ro, ki loo so Nigba t'a ba p'oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Eh eh eh eh eh eh mo wi t'emi o, ore ma di'ti Ko ma di'na orun mo 'ra e, o ti n f'ami han, Jesu o ni pe de Eru igi to n be loju re, lo gbe kuro, ko ye tenubole soro Lo ronu ko pa iwa da, ka si toro fun aanu K'a ju'wo ju'se k'a tuba f'Olorun, K'a le ba joba, k: a le ka wa mo won Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s'asaro aye re Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s'asaro aye re Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s'asaro aye re
Writer(s): Patricia Temitope Alabi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out