album cover
Kape Laye
1,541
Gospel
Kape Laye was released on August 17, 2012 by Gospel Vibez Ltd. as a part of the album Alagbara
album cover
Release DateAugust 17, 2012
LabelGospel Vibez Ltd.
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy
BPM75

Credits

PERFORMING ARTISTS
Tope Alabi
Tope Alabi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Patricia Temitope Alabi
Patricia Temitope Alabi
Songwriter

Lyrics

Kaape laye
Ka lo Ile aye titi
Ko ni Kaye gbo ooooooo
Aye lole lo niyan keee gbo
Igba ta gbe laye
Ohun a gbe Ile aye she gbogbo
Keledua je kaa le pitan rere
Omi aye to ru siwa seyin o
Awon kan gbaye
Won pitan iṣẹ titi
Wọn pitan ìṣòro kolopin rárá
Ọrọ wọn o Papa jasayo o'mase
O'jojo aye ni won fojú sògbérè ẹkun
Titi ikú fi p'awọn won o lenu dupẹ
Omi aye to ru siwa seyin ooo
Awọn kan gb'ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t'oda ayé
Ọrọ' ayé rú bo wọn lójú jọjọ alumoni
Wọn l'ayé wọn f'ogo rẹ fún satani nii
Igbagbe ṣewọn pé òun gbogbo tọwọ asèdá wa o'mase o'mase
Òun gbogbo toni kaluku ní wọn fi fesu
Written by: Patricia Temitope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...