Music Video

Music Video

Credits

PERFORMING ARTISTS
Tope Alabi
Tope Alabi
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Patricia Temitope Alabi
Patricia Temitope Alabi
Songwriter

Lyrics

[Chorus]
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko seni ta le fi safiwe Re o, O tobi
Ko seda ta le fi sakawe Re o, O tobi Oluwa
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko seni t a le fi safiwe Re o, O tobi
Ko s eda t a le fi sakawe Re o, O tobi Oluwa
[Verse 1]
O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo
Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun
Pupo pupo ni O, O koja omi okun atosa, O ga po
Ajulo O o se julo, O o se julo
[Chorus]
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s eni ta le fi safiwe Re o, O tobi
Ko s eda ta le fi sakawe Re o, O tobi Oluwa
[Verse 2]
Oba lori aye, O tobi o eh
Agba ni loko eru, Olominira to n deni lorun
O fi titobi gba mi lowo ogun tapa obi mi o ka
Olugbeja mi to ba mi rogun lai mu mi lo to segun
Akoni ni O o, Akoni ni O
[Chorus]
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s eni ta le fi safiwe Re o, O tobi
Ko s eda ta le fi sakawe Re o, O tobi Oluwa
[Verse 3]
B O ti tobi to oo, laanu Re tobi
B O ti tobi se o, ododo Re tobi o
O tobi tife tife, Onimajemu ti ki i ye
Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alailetan
Ogbon to koja ori aye gbogbo oh oh oh
[Chorus]
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko seni t a le fi safiwe Re o, O tobi
Ko seda t a le fi sakawe Re o, O tobi Oluwa
[Outro]
Akoko O tobi, O tobi o
Oluwa
Ipilese ogborin o yeye
O tobi
Ibere, Eni to fogbon da ohun gbogbo
Oluwa
Igbeyin ola nla, o la la o
O tobi
Opin aye a torun ko siru Re
Oluwa
O tobi, O o se sakawe lailai o
O tobi
Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi
Oluwa
Awon angeli won n ki O, O tobi se
O tobi
Olorun o pani ki iya o tan
Oluwa
O se pupo laye mi, O tobi o
O tobi
Iwo lo gb orin to o ga, to gun, to tun fe
Oluwa
O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la
O tobi
Written by: Patricia Temitope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out

Loading...