album cover

Cartoon

111,454Music2025
album cover
00:00
00:35
00:40
00:45
01:00
01:05
01:10
01:35
02:20
00:00
02:44
Past 7 Days
Cartoon was discovered most frequently in the first few seconds of the song during the past week

Lyrics

[Intro]
Hello
Marlians
Marlians Marlians
[Verse 1]
O ti lọ far far
Ko fa nnkan ti awa n fa
Cali la wa n fa
Colo loun fa
O ti lọ far far
Ko fa nnkan ti awa n fa
Cali la wa n fa
Colo loun fa
[Verse 2]
O ti lọ far far
Ọyọ loun wa
Eko lawa wa
Eko lọga wa
O ti cross border
Colorado loun wa
Awa wa ni California
Awọn ẹgbẹ ẹ wa ni Canada
[Chorus]
Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon (Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon)
Bọda ẹ ya were to malu (Bọda ẹ ya were to malu)
Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon (Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon)
Bọda ẹ ya were to malu (Bọda ẹ ya were to malu)
[Refrain]
Igbo ẹ da?
Bakky ẹ da?
Ada ẹ da?
Ake ẹ da?
Ibon ẹ da?
Bata ẹ da?
Ọmọ ase ile baba ẹ da?
Igbo ẹ da?
Bakky ẹ da?
Ada ẹ da?
Ake ẹ da?
Ibon ẹ da?
Bata ẹ da?
Ọmọ ase ile baba ẹ da?
[Verse 3]
O ti lọ far far
Ko fa nnkan ti awa n fa
Cali la wa n fa
Colo loun fa
O ti lọ far far
Ko fa nnkan ti awa n fa
Cali la wa n fa
Colo loun fa
[Chorus]
Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon (Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon)
Bọda ẹ ya were to malu (Bọda ẹ ya were to malu)
Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon (Ẹ ti high ẹ l'ọn wo bi cartoon)
Bọda ẹ ya were to malu (Bọda ẹ ya were to malu)
[Verse 4]
Pata nla, furọ nla
Kọmu nla fun ọlọyan nla
Wọn mọ iru ti ẹ nla nla
Baba ibeji oloko nla
Pata nla, big person
Kọmu nla, big bobby
One in the chamber fit kill person
At your own risk you can gbegẹ si
One in the chamber, chamber, chamber, chamber
Ha, big bobby, one in the chamber fit kill person
At your own risk you can gbegẹ si
[Verse 5]
O ti lọ far far
Ko fa nnkan ti awa n fa
Cali la wa n fa
Colo loun fa
O ti lọ far far
Ko fa nnkan ti awa n fa
Cali la wa n fa
Colo loun fa
[Refrain]
Igbo ẹ da?
Bakky ẹ da?
Ada ẹ da?
Ake ẹ da?
Ibon ẹ da?
Bata ẹ da?
Ọmọ ase ile baba ẹ da?
Igbo ẹ da?
Bakky ẹ da?
Ada ẹ da?
Ake ẹ da?
Ibon ẹ da?
Bata ẹ da?
Ọmọ ase ile baba ẹ da?
Written by: Azeez Fashola

Shazam Footer

Select language:
Google Play Store
Apple App Store
Chrome Web Store
Galaxy Store

Follow Us

Loading...