album cover
Ganja
album cover
Ganja was released on October 10, 2025 by Dapper Music & Entertainment as a part of the album Mr Bee
AlbumMr Bee
October 10, 2025
LabelDapper Music & Entertainment
BPM100
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Music Video

Music Video

Lyrics

[Chorus]
To ba ti de mule wa ni pe ṣo ma n ba, ma gba
To ba ti fẹla pa, ganja
Everyday la ma n fa a
Ọmọ boys them with him own trauma, trauma
I don see devil wey wear sutana L'Ajah
Mo ri pẹlu kala, gangster
Were pọ ni Naija
I no get choice
[Verse 1]
When I check my available
I see say na only me go carry my agbelebu
Cos everything no dey happen by miracle
And daddy mi dẹ ti try gan-an now emi lo ku
Ṣugbọn a ti kọ ọ ma la o daju
Nigba mi gbogbo nnkan kọ lowo gan-an ẹmi lo ju
Sani satani ya mi y'eṣu
Wetin I no fit see no dey controllable
[Verse 2]
Mo n lọ jẹjẹ mi ni o
Igi gogoro ma gun mi loju
At'okere ma ṣa ti gboju
Orin ni mo mọ to da mi loju
Oju yẹn ṣa lọ mo ohun to yonu
Mo mọ bi mo n lọ ẹ ma kan mi loju
Ade mi leke wọn o le da mi duro
Ẹru mi to pọ loṣuka fi wuwo
[Verse 3]
Wa a ni Mr Bee
Ọga olorin to n pa mi bi ọti
Ọdọ ẹgbẹ gan-an o jẹ fi ẹ tayin
Agba ni leather ma fi we kaki
Yeh, at'awọn fine girl melanin
Oyinbo mi pepper gan-an ni dakun ma pa mi
Ẹbọra rhythm, lord of harmony
O tun le kọ Fuji lori R&B
[Chorus]
To ba ti de mule wa ni pe ṣo ma n ba, ma gba
To ba ti fẹla pa, ganja
Everyday la ma n fa a
Ọmọ boys them with him own trauma, trauma
I don see devil wey wear sutana L'Ajah
Mo ri pẹlu kala, gangster
Were pọ ni Naija
I no get choice
[Verse 4]
When I check my available
I see say na only me go carry my agbelebu
Cos everything no dey happen by miracle
And daddy mi dẹ ti try gan-an now emi lo ku
Ṣugbọn a ti kọ ọ ma la o daju
Nigba mi gbogbo nnkan kọ lowo gan-an ẹmi lo ju
Sani satani ya mi y'eṣu
Wetin I no fit see no dey controllable
[Verse 5]
Mo n lọ jẹjẹ mi ni o
Igi gogoro ma gun mi loju
At'okere ma ṣa ti gboju
Orin ni mo mọ to da mi loju
Oju yẹn ṣa lọ mo ohun to yonu
Mo mọ bi mo n lọ ẹ ma kan mi loju
Ade mi leke wọn o le da mi duro
Ẹru mi to pọ loṣuka fi wuwo
[Outro]
Wa a ni Mr Bee
Ọga olorin to n pa mi bi ọti
Written by: Adewale Atanda
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...