album cover
Taloto
album cover
Taloto was released on August 16, 2026 by Aremmicllc as a part of the album Taloto - Single
August 16, 2026
LabelAremmicllc
BPM83
Melodicness
Acousticness
Valence
Danceability
Energy

Music Video

Music Video

Lyrics

[Chorus]
Ta lo to?
Ta lẹni ti n wi?
Ngba t'Oluwa o ba wi
Ta ni n tu?
Ta ni n de?
Ngba t'Oluwa o ba paṣẹ
[Chorus]
Ta lo to?
Ta lẹni ti n wi?
Ngba t'Oluwa o ba wi
Ta ni n tu?
Ta ni n de?
Ngba t'Oluwa o ba paṣẹ
[Chorus]
Ta lo to?
Ta lẹni ti n wi?
Ngba t'Oluwa o ba wi
Ta ni n tu?
Ta ni n de?
Ngba t'Oluwa o ba paṣẹ
[Bridge]
Mo ti fọrọ mi f'Oluwa, ooh
[Verse 1]
Ta lo n tu oh?
Nigba t'Ọlọrun ko tu
Ta lo de?
Nigba ti aṣẹda ko paṣẹ
Iwọ nikan l'Olutu, l'Olugbe, Olude
Ọlọrun iwọ nikan lo le ṣe
Bi Paulu ba n gbin
Bi Apollo ba n bomirin
Lai si ibukun rẹ nibẹ, asan bansa
[Verse 2]
Ta lo wi o?
Ti si n ṣe, nigba t'Ọlọrun ko paṣẹ
Ohun gbogbo, ẹda gbogbo ko a tọdọ Oluwa wa?
Eniyan ma ṣe kun, eniyan sọnu ko ma sọnu
[Verse 3]
Ta lo n ran?
Nigba to o ti de'bẹ
Ta lo n lọ o?
Nigba to o ni ko lọ
Davidi bere wi pe
"Ṣe ki n lepa?
Ṣe ma ba wọn?
Ṣe ma ri gba o?"
Iwọ nikan l'alaṣẹ aye
Alaṣẹ ọrun
Baba o
Iwọ nikan l'alaṣẹ aye
Alaṣẹ ọrun
Baba o
[Verse 4]
Okun ri ọ, o sa (O sa)
Jọdani pada sẹyin
Okun ri ọ, o sa ohh
Jọdani pada sẹyin
Iwọ nikan lokun ri to sa o
O sa ere
Jọdani pada sẹyin
Ta lo n paṣẹ niwaju apaṣẹ?
Apaṣẹ, apaṣẹ, apaṣẹ to n paṣẹ aye mi
[Verse 5]
Ọwọ rẹ lo n gbe mi nija (Iwọ ni)
Agbara rẹ lo n gbe mi ro (Iwọ ni)
Ipa rẹ lo n wo mi san (Iwọ ni)
Iwọ, Iwọ nikan (Iwọ ni)
Iwọ, Iwọ nikan (Iwọ ni)
Ma duro jẹ, to o ba lọ, mi o lọ
Mu mi rin, ki n ma sọnu
Pa a laṣẹ ki n tẹle ọ, ye
Ọwọ rẹ lo n gbe mi nija (Iwọ ni)
Agbara rẹ lo n gbe mi ro (Iwọ ni)
Iwọ, Iwọ nikan (Iwọ ni)
Ni ma a tẹle
[Outro]
Ta lo to ọ o?
Ta lẹni ti n wi?
Ohun t'Oluwa o wi
Ta lo n de e?
Nigba ti aṣẹda ko paṣẹ
Written by: Michael Ajetomobi, Tope Alabi
instagramSharePathic_arrow_out􀆄 copy􀐅􀋲

Loading...