Music Video

Featured In

Credits

PERFORMING ARTISTS
Brymo
Brymo
Performer
COMPOSITION & LYRICS
Olawale Olofo'ro
Olawale Olofo'ro
Songwriter
PRODUCTION & ENGINEERING
Mikkyme Joses
Mikkyme Joses
Producer

Lyrics

Alelúyà méje-méje Òṣèlú pé jọ f'ọjọ méje Wọn fẹ tó'lú lójó méje Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese Alelúyà méje-méje Àwọn ojẹlú fèrègé Wọn l'awọn Ọmọ Yepa tún tí dé Wọn fẹ dá'lúrú, m'èrè lè Alelúyà méje-méje Akonilẹ́rú wọn tún tí dé Wọn fẹ sọ bo'ṣè má má gbé Iwo f'okun s'ọrun òun ṣiṣẹ agbe Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese Wọn l'awọn omidan ló m'àiyé lè Wọn fẹ jẹka, wọn fẹ ro ṣọ Oko ló m'àiyé ọkùnrin lè B'okọ iwájú sí e k'ota Bò bá k'ẹyín sí e k'ota Bò ba kú iwọ nìkàn ṣé òun olèṣe Ma gbàgbé ibí o ti ńbabọ' o B'okọ 'wájú sí ẹ k'ota Bò bá k'ẹyin sí ẹ k'ota Bò ba kú iwọ nìkàn ṣé òun olèṣe Ma gbàgbé ibí o ti ńbabọ' o Alelúyà méje-méje (à re pé paropa) Adalérú wọn tún tí de (à re pé paropa) Kò fẹ' k'ọmọ o mo bàbá rẹ (à re pé paropa) Kò fẹ' k'ọkọ o gbọ t'àyà rẹ (à re pé paropa) Gbogbo iṣẹlẹ korin-kese (à re pé paropa) Wọn l'awọn omidan lo máyéle (à re pé paropa) Wọn fẹ Jẹká, wọn fẹ roṣọ (à re pé paropa) Oko ló m'àiyé ọkùnrin lè (à re pé paropa) Eh-ya, yah, ya
Writer(s): Olawale Ibrahim Ashimi Lyrics powered by www.musixmatch.com
instagramSharePathic_arrow_out